Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
Eeh eeh eeee
It's Timilehin oh oh
Call me Zinoleesky
[Verse 1]
Ẹlẹburuikẹ ma gbagbe mi Ayanfẹ
Ma foju mi sọna gan-an jẹ kayọ mi dalẹ
Cos I be da kind boy wey dem no too sabi
But I sabi myself cos I know who I be
Wọn fẹ ja ranki mi ko jọ
Ba mi gbẹru mi gbe tan
Ẹ ma gbọ starting ẹ le gbọ tan
[Verse 2]
O ya tell me DJ ki n raparegangan
Mo ti hustle loru ki n le gbadun lọsan
Kekere l'ọn ti n sọ fun mi pe
Mo ma deyan ti n ba ti jẹ kori mi pe
O ya stand gidigba mi o fọ
Tori mugu mi leeyan
Oriire o ki n ṣe fun eeyan kan
Padi se fun eeyan kan
Mo ti gbadura mo gba awẹ
Kayọ mi le dalẹ
Ki n mommy le jere ọmọ
Adio mo mi n tẹramọ
Yeh eh eh eh
[PreChorus]
Mọnamọna tanna ọmọ oloore fẹ ṣina
Baba ṣilẹkun ayọ kemi le rọna lọ
Mọnamọna tanna ọmọ oloore fẹ ṣina
Baba ṣilẹkun ayọ kemi le rọna lọ
[Chorus]
Ooh ooh aah kokoko
Ki la ti kọ gan-an t'ọn lo to
Fun wọn ni lamba jẹ k'ọn jo
Sebi wọn ni fake ni oje lo n lo
[Chorus]
Ooh ooh aah kokoko
Ki la ti kọ gan-an t'ọn lo to
Fun wọn ni lamba jẹ k'ọn jo
Sebi wọn ni fake ni oje lo n lo
[Verse 3]
Ẹlẹburuikẹ ma gbagbe mi Ayanfe
Ma foju mi sọna gan-an jẹ kayọ mi dalẹ
[Verse 4]
A ti kọ, kọ, kọ, kọ ewo la ma kọ gan-an k'ọn to gbọ
Iṣu parada o di iyan
Agbado parada o dẹkọ
Wetin go be go be
Eeyan lo bi Mikel Obi
Oluwa change story mi kaye mi ladun ko loyin
[Verse 5]
Ah, ma gbabe mi Ọlọrun
To ba ti ni mi o kọ Ọlọrun
Ba mi ṣe ko dun, ko pọ, ko pẹ
Ki ile-aye yii dajẹpẹ yeh
Where the bad man dey?
Who talk sey my hustle no go pay?
Ẹ forin pa wọn kẹ dẹ ṣe wọn leṣe
Kẹ kan wọn lapa kẹ fi ge wọn lege, ah
Wọn lorin mi o da
Mo ri pata yin n'gba yẹn mi o ka
Mo ni kẹ gbe igba yin mo yọnda
K'Ọlọrun gba wa lọwọ alakoba
You have to face it don't run
Time wait for no one
Pls paint your motherland
Go check what's up on the other side
Yeh i yeh, orin lo n bẹ nikun mi ti DJ fẹ gba jingle mi
[PreChorus]
Mọnamọna tanna ọmọ oloore fẹ ṣina
Baba ṣilẹkun ayọ kemi le rọna lọ
Mọnamọna tanna ọmọ oloore fẹ ṣina
Baba ṣilẹkun ayọ kemi le rọna lọ
[Chorus]
Ooh ooh aah kokoko
Ki la ti kọ gan-an t'ọn lo to
Fun wọn ni lamba jẹ k'ọn jo
Sebi wọn ni fake ni oje lo n lo
[Chorus]
Ooh ooh aah kokoko
Ki la ti kọ gan-an t'ọn lo to
Fun wọn ni lamba jẹ k'ọn jo
Sebi wọn ni fake ni oje lo n lo
[Outro]
Ẹlẹburuikẹ ma gbagbe mi Ayanfẹ
Ma foju mi sọna gan-an jẹ kayọ mi dalẹ
A ti kọ, kọ, kọ, kọ ewo la ma kọ gan-an k'ọn to gbọ
Iṣu parada o di iyan
Agbado parada o dẹkọ
Written by: ONIYIDE AZEEZ, Salako Oluwatimilehin
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...