Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ywc Dsquare
Ywc Dsquare
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Duru Oluwasegun Daniel
Duru Oluwasegun Daniel
Composer
D-Square
D-Square
Lyrics
PRODUCTION & ENGINEERING
Super beatz
Super beatz
Producer

Lyrics

[Intro]
We gat Dsquare
Ya gat bars for me
Mother fucking bars
You sure ya gat bars?
Mother fucking bars
Hit shit ****
[Verse 1]
What if ti ko ba si rapper to le handle mi?
Ti mo di best rapper ti Eminem o ni le tackle mi
Ṣo ti lọ church Cele kankan ri ti wọn o lo candle ni?
Ọkunrin ni mi but obirin naa le rough handle mi
[Verse 2]
What if to ba jẹ emi ni giant of Africa?
T'ọn ba gbe Grammy fun mi ki ni Burna fẹ ba mi fa?
You wanna fuck with me ko possible k'eeyan kan ba mi da
Nibo lati ma ri'gbo t'ọn ba la wọn fẹ ba mi fa a
[Verse 3]
Wọn lagba la wọn rapper ka lọ fi shovel feature rake
What if ta ba lọ fi local rap feature Drake?
Headdies ati Grammy ṣ'ọn ma fun mi ni piece of cake?
T'ọn ba fun mi piece of cake ṣ'ọn ni pada underrate?
[Verse 4]
What if ti ko ba si youth to mọwọ internet?
Ibọn l'awọn **** ma ma gbe ki lo n jẹ talent?
What if ti ba sọ pe mo fẹ di Nigerian president?
Ṣ'ọn ma vote fun mi regardless of local residence?
[Verse 5]
Worthy is the name, oh Jesus is lord
What if to ba dọrun to lọ ri pe Jesus is lord?
To lọ ri costume yellow pẹlu anchor
Ajitu to lo gbowo ni CBN ti gba handcuff
[Verse 6]
What if to ba jẹ pe naira lo ju dollar lọ?
Shout-out s'Oluwadollarz baller to ju baller lọ
Boya burna stove wọn lo fẹ ju Burna Africa lọ
Mommy Dollarz ni rapper to ju rapper Ghana lọ
[Bridge]
Babe am bored at home (Olosho in disguise)
Who's gonna take me out? (Olosho in disguise)
Disappearing messages (Olosho in disguise)
Babe he's my bestie (Olosho in disguise)
[Verse 7]
What if ti iyawo t'Ọlọrun kọ mọ ẹ ti di olosho?
Ṣo ma gba iyawo oniyawo ni abi o ma gba kamu?
Padi ẹ to foju pa ẹ rẹ lana leni to d'olowo
Ṣo ma create enemity ni abi o ma gba kamu?
[Verse 8]
What if to ba j'omi nikan lo wa lara ko s'ẹjẹ?
Wọn ni ilu ti o ba ti sofin wọn ni ko s'ẹsẹ
Ika to ba ṣ'ọba lọba ma ge danu, wo ko sẹbẹ, ẹ jẹ bẹẹ
Baddoo lọba industry wo ko s'ẹgbẹ ẹ
[Verse 9]
What if my congrats bring you to my DM?
Ti mo look away bi n pe mi o ri ẹ
To ba j'aarọ la wa ma ya sọ fun ẹ pe ko GN
O ṣe wa jẹ'gba ti mo ṣoriire lo wa n DM?
[Verse 10]
What if to ba j'emi larole MC Oluomo?
N bu iya bu baba iwọ to be da si n bu ọ mọ
Ọpọlọ wọn sunki ẹ sọ fun wọn k'ọn ṣe brain check
Iwọ to fẹ gbe mi trabaye ko gbe mi de'bẹ
Orita Fọgo la wa t'ọn ba bi yin da kẹ cross ẹ
T'awa ba ti n drop shit awọn ni k'ọn ma flush ẹ
I'm dropping some sick bars ẹ wa ba mi nurse ẹ
Ẹni ba gbemu ẹyin t'emi ṣe ni kẹ crush ẹ
[Verse 11]
What if am fucking flying like a plane sex?
I will know from my fans if my rap doesn't make sense
I'm topping you this rapper set awọn Baddoo ni mi
Shadow ati iku ti jẹlẹ so set awọn Baddoo ni mi
[Verse 12]
Ootọ ọrọ re this is fact
O sanra gan-an this is fat
This is protein this is fat
This is rap this is verse
This is alpha this is last
All these crew don dey cast
Present this is past
This is drug this is jazz
[Verse 13]
Wọn fẹ hold time wa tori wọn o ri future
Imagine pe Lil Wayne kan lọ pe mi pe ka jọ feature
What if t'ọn ba lọ block Instagram pẹlu TikTok?
Pupọ ninu wọn a gbagbe talent most wọn a give up
[Verse 14]
What if to o ba mọ pe Tunde Ednut lo ni IG?
Bawo lo ṣe fẹ mọ pe B.O.D lo ni Twitter?
What if to o ba mọ pe babalawo lo ni IP?
Shout-out s'awọn alfa to n paṣẹ pẹlu tẹsuba
[Verse 15]
What if one Chief con steal something?
Ṣe iya tẹ fi jẹ talaka naa lẹ ma fi j'olowo?
What if I dey for street I no get nothing?
Ṣe iwa tẹ wu si talaka naa lẹ ma n wu s'olowo?
[Verse 16]
What if I offer you my skin and I collect all your bone?
I offer you my sim and I collect all your phone?
I offer you my kidney I collect all your soul?
I offer you my camera I collect all your drone?
What if Dsquare con go to hell?
Ẹyin followers ori Instagram ṣẹ ma tẹle mi?
Written by: D-Square, Duru Oluwasegun Daniel
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...