Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Barry Jhay
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Barry Jhay
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Olawale Michael Adibe (Dibs)
Producer
Lyrics
[Intro]
Oh-oh-oh oh uh-uh-uh
Uh-uh-uh uh uh-uh, ye
(Mad-Madaroad)
Oh-oh uh-uh-uh uh ye-ye uh oh
Ye-ye, ye
[Verse 1]
Say, I don't force it
I just let the spirit lead, 'cause I know
Yes, I know You are with me all the way
[Chorus]
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipo padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lo wa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹ mi le o, ah (ẹru ògo rẹ ń ba mí)
Ẹlẹwa ògo (Hm), Àdàbà Mímọ, jọwọ, bale mí o oh-oh (Emi ọmọ rẹ re e)
Mo dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ń ṣe
Ẹmi-Mimọ, jọwọ, wá gbé mi fo o
Mo fẹ ga nínú wọn (Gbà mí gbọ)
Má ṣẹ gbara le wọn, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye oh
Má ṣe gbara le wọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, yeah-oh
[Verse 2]
Ìrìn yii mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣe d'Ọlọ́run mí mú o
(Ní mo ṣe gbà Ọlọ́run mí mú ṣinṣin)
Bí Olùwà ṣe ń sọla ìyẹn nínú ọlá
Bẹ ní yoo tun ṣògo, ohh, Ọlọrun mí ògo
[Chorus]
My Father, My Father, Ọlọrun ti ko kí ń yipo padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lo wa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹ mi le o, ah (Ẹru ògo rẹ ń bá mí)
Ẹlẹwa ògo (Hm), Àdàbà Mímọ, jọwọ, ba le mí o oh-oh (Emi ọmọ rẹ re e)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ń ṣe
Ẹmi-Mimọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
Mo fẹ ga nínú wọn (Gbà mí gbọ)
Má ṣe gbara le wọn, má ṣẹ gbẹkẹ le enìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀le ènìyàn asán bansa, ye oh
Má ṣe gbara le wọn, dákun, má ṣe gbẹkẹle'nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh
[Outro]
(Sunshine on the mix)
Written by: Barry Jhay