Lyrics

Ololufe mi, ti e ni mo fe Alayanfe mi, ti e ni mo fe Ololufe mi, mi o se tiwon mo Alayanfe mi, ti e ni mo fe Wa f'enu ko mi l'enu, oh-oh Wa f'ara ro mi l'ara o Eh, eh, eh, eh, eh, eh Alayanfe mi, ti e ni mo fe Ololufe mi, ti e ni mo fe Alayanfe mi, mi o se tiwon mo Alayanfe mi, ti e ni mo fe Wa f'enu ko mi l'enu Wa f'ara ro mi l'ara o Oh, oh, oh, oh, oh
Writer(s): Fela Anikulapo Kuti Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out