Crédits

INTERPRÉTATION
Brymo
Brymo
Interprète
COMPOSITION ET PAROLES
Olawale Olofo'ro
Olawale Olofo'ro
Paroles/Composition
PRODUCTION ET INGÉNIERIE
Mikkyme Joses
Mikkyme Joses
Production

Paroles

[Verse 1]
Èmi ni, èmi lẹni náà
Ọkùnrin mẹta àtààbọ t'ọn forin kọ
Èmi ni, èmi lọmọ náà
Ọkùnrin mẹrin àtààbọ, wọn ń tẹnu mọ
Mo lanu, mo sọrọ
Mo yọ àáké, mo fọ ọrọ
Ọmọ ọlọfọọrọ
Mo j'àkàrà ọfọọrọ
Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni t'ọn sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn màmá gan-an ń sòró ní pópó
[Chorus]
Wọn lémi l'àkọ́kọ́
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh
[Verse 2]
Èmi ni ọkùnrin náà
T'áwọn màjèsín ń sọ po morin gan-an
Èmi ni, èmi l'ọmọ náà
Gbogbo ará àdúgbò ló ń tẹnu mọ
Èmi bàbá olówó
Mo ṣòwò, mo jèrè
Ìwà àti ọpọlọ ló ń lò
Àwọn ọtá ti rupóò
Èmi ni áà, emi ni óò
Èmi mà l'ẹni t'ọń sọ nígboro
Èmi ni yáà, èmi ni yóò
Àwọn ọmọge ń rèdí ní pópó
[Chorus]
Ah, wọn lémi l'àkọ́kọ́ (Iwọ l'àkọ́kọ́)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́ oh)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́ oh)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́ (Iwọ l'àkọ́kọ́)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́ oh)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́)
Wọn lémi l'àkọ́kọ́, oh oh (Iwọ l'àkọ́kọ́, oh)
Written by: Olawale Olofo'ro
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...