Clip vidéo
Clip vidéo
Crédits
INTERPRÉTATION
Emmanuel Adeniran
Basse électrique
David Soji Ijaduola
Batterie
Charles Shittu
Guitare
Emeka Osuji
Piano
COMPOSITION ET PAROLES
Emmanuel Adeniran
Paroles/Composition
Abiola Dosunmu
Paroles/Composition
PRODUCTION ET INGÉNIERIE
Emmanuel Adeniran
Production
Jason Emberton
Ingénierie de mastérisation
Paroles
Ọmọ bàbá ni mo jẹ́
Àtúnbí nípa ẹ̀jẹ̀ ẹ rẹ̀
Hmmmmm
Mo di ẹ̀dá títún
NÍtorí ó kú fún mi
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
O ti dẹ́
O ti dẹ́ o
Ẹni tí mo jẹ́ tẹ́lẹ̀ ti do o hun Ìgbàgbé
KÍyèsi mo dọmọ titun
ahhhh
Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé o gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá
Èmi yìí náà mo ṣákolọ
Mo dẹ̀ ṣe ìfẹ́
ìfẹ́ inú mi
Èmi yìí náà mo wùwà ìkà
Ah
Síbẹ̀sí
Síbẹ̀sí o forí jì mí
O hun àtijọ́ o ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
O ti dẹ́ o
Èmi ọmọ tó ti kú, tó sì tún yè
Ah
Èmi ọmọ tó sọnù
Tó sọnù tí a sì ríi
Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá
Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Written by: Abiola Dosunmu, Emmanuel Adeniran


