इसी प्रकार के गाने
क्रेडिट्स
PERFORMING ARTISTS
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Olofo'ro
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Mikkyme Joses
Producer
गाने
Ifẹ mi, dariji mi
Ọmọ de n ṣe mi
Afarawe o ṣe temi
Ka da duro ni mo wari
Mo ti sọ tẹlẹ-tẹlẹ ri
Igboro o ma rerin ri
Ijakadi lo mu niṣẹ
Ka ro ori o b'ọpọ ṣíṣẹ
Bi n ba fa a, w'ọn l'ole
Bi n ba túlẹ̀, wọn lo rọ
Bi n duro wọn ma mu ere
Bi n ba sa, wọn ni mo kere
Aba lọ, aba bọ
Bo wun wọn k'ọn para wọn o
Oun ani la n nani
Temi ni temi
Awelewa f'ori ji mi
Mo lakaaka ki n to debi
Rírọ mẹdẹ o ṣe temi
Nibi lile la n b'ọkùnrin
Ifẹ rẹ ṣa loduro ti mi
Odudu, b'ofunfun, bo pupa
Ifẹ rẹ ṣa lo mu'nu tumi
Ninu eerun at'ojo, at'ailera
Bi n ba fa a, w'ọn l'ole
Bi n ba túlẹ̀, wọn lo rọ
Bi n duro wọn ma mu ere
Bi n ba sa, wọn ni mo kere
Aba lọ, aba bọ
Bo wun wọn k'ọn para wọn o
Oun ani la n nani
Temi ni temi
Aba lọ, aba bọ
Temi lo jẹ la'lẹ oni o
Gbogbo igba ti o ba lọ
Mo mọ o pada wa
Writer(s): Olawale Olofo'ro
Lyrics powered by www.musixmatch.com