Video Musik

Video Musik

Dari

PERFORMING ARTISTS
Danny S
Danny S
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Daniel Oko Olaborode
Daniel Oko Olaborode
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Shocker
Shocker
Producer

Lirik

[Intro]
Ege, Ege, Ege, ege
Shocker lo ṣe beat
Gbẹsẹ, call me Danny S o, ege, ege
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Shakushaku (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Awọn ọmọ wobe (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Verse 1]
Wa wo telli, wa wo telli, wa wo telli, wa wo Balotelli
Pamutubu, pamutubu, pamutubu ka ma fẹgbẹgbẹ rin
Ko-ko-ko wọle ko fẹgbẹgbẹ rin
Mo ti ṣaṣẹ gbowo mo le fẹgbẹgbẹ rin
Awọn ọmọ poly ẹ fẹgbẹgbẹ rin
Awọn ọmọ uni ẹ fẹgbẹgbẹ rin
Awọn ọmọ wobe da? Awa re, awa, awa re
Shaku Shaku da? Awa re, awa, awa re
You want to make money ko taka oṣi danu
Ye, you want to count money ko taka oṣi danu
Ye, blessing dey follow me mo taka oṣi danu
Ehh, some people want to mi mo taka oṣi danu
[Bridge]
****, ****, gbẹsẹ, ma sun
Ma ma jẹ k'ọn kanna candle si ẹ lẹsẹ
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Shakushaku (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Awọn ọmọ wobe (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Verse 2]
Fun wọn lege Okocha
Eeyan Pasuma wonder
Sare wọle ko jẹ western lotto
To ba ge ẹ ọmọ ọpẹ sare lọ to
Awon omo wobe da
Shaku Shaku da
You want to make money ko taka oshi danu
Ye, you want to count money ko taka oshi danu
Ye, blessing dey follow me mo taka oshi danu
Eh, some people want to mi mo taka oshi danu
[Bridge]
****, ****, gbẹsẹ, ma sun
Ma ma jẹ k'ọn kanna candle si ẹ lẹsẹ
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Shakushaku (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Chorus]
Me and you (Ege)
One on one (Ege)
Awọn ọmọ wobe (Ege)
Off the light (Ege)
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
Fun wọn ni leg over ma ṣeka, ehh
[Outro]
Ọmọ Jesu (Ege)
Tata (Ege)
Oba goal (Ege)
Elc (Ege)
Abu Abel (Ege)
Charles Lawal (Ege)
Dolly Pizzle (Ege, ege, ege)
Salary
Zigi Zigi, Shigo wa n le o
All the way from Iju
Awọn ọmọ Shaolin Temple
All the way from Ilu Shakushaku
Awọn ọmọ ijọba Gurumanguzu
Call me Danny S o
Shocker lo ṣe beat
Written by: Daniel Oko Olaborode
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...