Dari

Lirik

[Verse 1]
Layemi
Sọ fun wọn mo nifẹẹ ẹ, mo nifẹẹ ẹ gan-an ni
Fine lady girl you different, you different gan-an ni o
I no know why but mo miss ẹ, mo miss ẹ gan-an ni
Bad girl, I'm addicted, addicted gan-an ni
[Chorus]
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ (Gi-gi, giddem)
[Bridge]
Hmm, sọ fun wọn mo nifẹẹ ẹ
Mo ni Folashade
Sọ fun ẹ pe mo nifẹẹ ẹ, mo nifẹẹ ẹ gan-an ni
[Verse 2]
Layemi
Olayemi mo nifẹẹ ẹ
Funke sọ fun ẹ mo nifẹẹ ẹ
Titilola
Hmm, sọ fun ẹ mo nifẹẹ ẹ
Mo ni Folashade
Sọ fun ẹ pe mo nifẹẹ ẹ, mo nifẹẹ ẹ gan-an ni
[Chorus]
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ
[Verse 3]
Ko-ko-ko-ko
Konko below ko-ko-ko
O wa fẹ pade mi ni isalẹ
O yẹ ka fun un ko-ko below
Ko-ko-ko-ko
O wa fẹ jẹ ko-ko-ko-ko
Mo ni ko pade mi ni isalẹ
Iyẹn gan-an lo ṣe koko
[Chorus]
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi mo nifẹẹ rẹ
[Refrain]
Layemi
Olayemi mo nifẹẹ ẹ
Funke sọ fun ẹ mo nifẹẹ ẹ
Titilola
Hmm, sọ fun ẹ mo nifẹẹ ẹ
Mo ni Folashade
Sọ fun ẹ pe mo nifẹẹ ẹ, mo nifẹẹ ẹ gan-an ni
[Outro]
Gbe mi de'bẹ
Gbe mi, gbe
Gbe mi de'bẹ, gbe
Gbe mi de'bẹ
Gbe mi
Gbe mi de'bẹ
Written by: Ayodeji Ibrahim Balogun, Olajumoke Olayiwola, Oluwatobi Ojosipe, Peace Emmanuel Oredope
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...