Testi

Qudusi idán (2t upon the beats) Idán gangan, idán Ọmọ Mọriamọ, idán (idán o-o) Qdot l'orúkọ mí Wọn mòpé emi ni idán (idán) Idán tí ó wẹ tó ń dán (idan) Qudusi idán (idán) Idán kí dàn (idán) Báwo l'áyán Lekki ṣé ń dan? (Idán) Àdánwò o kin ńse ọrẹ idán (idán) Gbowó lọwọ Palmpay (idán) Ko fi sanwó Opay (idán) Idán o gbọdọ sùn (idán) Tori Yanki o ni pẹ ji (idán) Owó olówó l'égún na (idán) Ootọ ni Peller ńpá dan (idán) Obesere lóhùn lọ Ọba idán (idán) Sugbọn, idán gangan lonju idán (idán) Oùn lomu Sọdiki ọgbọnn (idán) Gan lọ gbà arodan fún dan (idán) Ẹ wọn mì sì tàn omidan (idán) Kẹ to gbé tan le tan (idán) Ẹma jẹ dan mọ dan (idán) Ki idán ma ṣẹrù fún omidan (idán) Idán wey slap popo (idán) Idán no dey sleep (idán) Na sleep dey wait for idán (idán) Idán òní wówó kiri (idán) Owó ló má ń wa 'dán (idán) Idán na him be the don (idán) Na why idán dey sit down (idán) Alhamdulillah (idán) Mo mọpé ẹ ti jẹ yẹn tán (idán) Ọlá Olùwà o kín tán (idán) Lamba mi o le tán (idán) Kàkà ki idán jabọ sí kòtò (idán) Mọnamọna ma tàn (idán) Idán na don (idán) Idán na high don (idán) Don Jazzy gan bẹ'rù idan (idán) Wọle Soyinka tio bẹ ru idán ni Ori ẹ ma dán (idán) Adan bi t'ogidan (idán) New Edition, idán (idán) Fẹnu ro dan (idán) Fẹnu wù igi odán (idán) Ma ba wọn fẹnu lu gángan (idán) Ma wo ojú ko tọ fẹnu jù 'dan (idán) Idan ju 'dan lọ (idán) Loni yan-yan, yan-yan, yan Olè sọrọ, online lowa (idán) Chicken, ò lè fò bi ẹyẹ àdán (idán) Eku ni ifá ńjẹ (idán) Adífá lonjẹ màlúù (idán) Idan no be yahoo (idán) Idán to ń dàn (idán) From Bourdilon to Aso Rock (idán) Jagabanu ní idan (idán) Mo mọ awọn idán gangan IBD Dende, idán Ọmọ Egungbohun, idán Ṣeyi Tinubu, idán Baddy Osha idán Lanre Typical, idán Kosi idán kàn ton tá mọto Lẹyìn Arowolo, idán MC Oluọmọ, idán Riliwanu Cooler, idán Ọba Sheffield, idán Kunle Poly, idán Tafa Sego, idán Kazeemu Elesu, idán Kapa Owoẹyẹ, idán Ọkanlọmọ, idán Ajibola Pasuma, idán Mo mọ Fẹmi Joro, mo mọ Fẹmi Jaguar Abu Abel, idán Sammy Larry, idán Tarry Shiny, idán Anọbi tiwa ni Mushin Mo mọ Lawali l'Abuja Mo ṣe bà Oníbà of Ibà Billique, idán Maverick, idán Doctor Brown, idán Bobrito, idán Mo mọ Wale ticket Kazzy lo fi idán sí mọto Eniola Tizzle, idán Ọlọfin Snipper, idán Ẹgbọn mi Bunmi Obakoya Tunla of Lagos, idán Mo mọ Bishop nílù Turkey Mo mọ Dandy, mo mọ Otunba Kashy Ọmọ Ayilara mi, ọrọ pọ Ọmọba Kumasi Ikorodu wa, say boko, Alabi Spatarcuz Baba Rado, Qdot l'oruko mi 2T upon the popo o-o (2T on the mix)
Writer(s): Daniel Bmice Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out