album cover
Wire
105
World
Wireは、アルバム『 』の一部として2026年5月30日にNGwide MediaによりリリースされましたWire - EP
album cover
アルバムWire - EP
リリース日2026年5月30日
レーベルNGwide Media
メロディック度
アコースティック度
ヴァランス
ダンサビリティ
エネルギー
BPM109

ミュージックビデオ

ミュージックビデオ

クレジット

歌詞

[Intro]
Ijọngbọn
[PreChorus]
Wire dun gan-an wire lo ma n fun mi joy
Mo gba wire ẹ wa ni ki n ma flenjo
Shock anybody mo fun wọn ni high tension
Owo mo fẹ alaye, mi o fẹ ẹjọ
Ti n ba gba wire aje ma be happy
Getting money iyẹn dẹ ni my hobby
Young and getting it Mr me YAGI
Emi ti mo ji ma sun mo gbe lappy
[Chorus]
Ehn, walahi walahi
Wire dun gan-an walahi
Ti n ba gba wire bai
Ma lọ jaye pa ni Dubai
Ti IRS ti drop
Ka ma lọ club ka lọ pop
Mu CC yẹn wa jẹ ki n top
Lọ ṣa Facebook abi Tiktok
[Bridge]
Omo ase ji ma sun
Ji ma sun ọmọ ase
Ko le gba wire o ti ye ẹ
Ọlọhun sẹ
[Verse 1]
Ah, gba wire ko frown
Gba wire ko rude
Tẹpamọṣẹ ko dẹ ye ma jowu
Btc yẹn lo jẹ ki n ma gawu
Joy wan kill me ti maga mi ti dawo
Owo ti drop o ti jabọ sinu aza
J'a lọ jaye ka lọ fagbo ninu zanga
Bẹbẹ n lọ mo dẹ n ball bi Jowi Zaza
Saint sami ganja, saint sami wire
[PreChorus]
Wire dun gan-an wire lo ma n fun mi joy
Mo gba wire ẹ wa ni ki n ma flenjo
Shock anybody mo fun wọn ni high tension
Owo mo fẹ alaye, mi o fẹ ẹjọ
Ti n ba gba wire aje ma be happy
Getting money iyẹn dẹ ni my hobby
Young and getting it Mr me YAGI
Emi ti mo ji ma sun mo gbe lappy
[Chorus]
Ehn, walahi walahi
Wire dun gan-an walahi
Ti n ba gba wire bai
Ma lọ jaye pa ni Dubai
Ti IRS ti drop
Ka ma lọ club ka lọ pop
Mu CC yẹn wa jẹ ki n top
Lọ ṣa Facebook abi Tiktok
Written by: Nwankwo Uche Emmanuel
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...