가사

Ó fúruru lóòréré o Àilaá bàbá kenyenyen l'éjgbó Ilé Ifon mo ti wá bàbá Èjìgbò réré mo tibò Oni nimi e yá wá wòrò Eyà wá wòrò. Ewa wése! E ma wá woró elésè kan bàbá Eyà wá wòrò. Ewa wése! E ma woró olójú kan bàbá E Eyà wá wòrò. Ewa wése! E ma wá woró alápá kan bàbá É ma wá wèrò léyín mi o! É ma wá wèrò Léyín mi
Writer(s): Luciana De Souza Barauna, Iuri Ricardo Passos De Barros, Yomar Passos Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out