크레딧

실연 아티스트
Brymo
Brymo
실연자
작곡 및 작사
Olawale Olofo'ro
Olawale Olofo'ro
송라이터
프로덕션 및 엔지니어링
Mikkyme Joses
Mikkyme Joses
프로듀서

가사

Ifẹ mi, dariji mi Ọmọ de n ṣe mi Afarawe o ṣe temi Ka da duro ni mo wari Mo ti sọ tẹlẹ-tẹlẹ ri Igboro o ma rerin ri Ijakadi lo mu niṣẹ Ka ro ori o b'ọpọ ṣíṣẹ Bi n ba fa a, w'ọn l'ole Bi n ba túlẹ̀, wọn lo rọ Bi n duro wọn ma mu ere Bi n ba sa, wọn ni mo kere Aba lọ, aba bọ Bo wun wọn k'ọn para wọn o Oun ani la n nani Temi ni temi Awelewa f'ori ji mi Mo lakaaka ki n to debi Rírọ mẹdẹ o ṣe temi Nibi lile la n b'ọkùnrin Ifẹ rẹ ṣa loduro ti mi Odudu, b'ofunfun, bo pupa Ifẹ rẹ ṣa lo mu'nu tumi Ninu eerun at'ojo, at'ailera Bi n ba fa a, w'ọn l'ole Bi n ba túlẹ̀, wọn lo rọ Bi n duro wọn ma mu ere Bi n ba sa, wọn ni mo kere Aba lọ, aba bọ Bo wun wọn k'ọn para wọn o Oun ani la n nani Temi ni temi Aba lọ, aba bọ Temi lo jẹ la'lẹ oni o Gbogbo igba ti o ba lọ Mo mọ o pada wa
Writer(s): Olawale Olofo'ro Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out