album cover
COLD
12
Afro-Beat
COLD은(는) 앨범에 수록된 곡으로 2025년 9월 17일일에 7480652 Records DK에서 발매되었습니다.COLD - Single
album cover
발매일2025년 9월 17일
라벨7480652 Records DK
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지
BPM100

뮤직 비디오

뮤직 비디오

크레딧

실연 아티스트
Philip Ayomide Akeju
Philip Ayomide Akeju
백그라운드 보컬
작곡 및 작사
Philip Ayomide Akeju
Philip Ayomide Akeju
작사가 겸 작곡가
프로덕션 및 엔지니어링
Akum Hits
Akum Hits
프로듀서

가사

Yeah
Waaa
Mo shì n'áwon wounds, kọkan tání kòní sann
Shóma gbàmí, àbí òní gbàmí lọ'rọ tí mo bá ORÍ sọ
Àjẹ ń jà fún ọmọ rẹ, tóbá délé kòní sọ
Óbàmí mín le guide, inelastic collision
Times I can't see the vision, walk bí ẹni tí ó ní mission
Dream tinnn dabi delusion, soldier tinnn lack ammunition
Time to make the decision, shóma like evolution
Orí ń crave revolution, kọmọ pákó dii golden son
Mio mọ'na tí ma gbe gbà, mio gbọ pà bíti àréé ìkà
Yépàpàrì pàrìpà, wọ'n fẹ ma dull high caliber
Kí àlùbáríbáríkà, ishẹ lóma pa tálíkà
Gbé SK ninu carighan, fi CO le mo fárígà
Arrrgh!
Ọmọ mi o 4–0 ooo, life give me 4–0
Oun binu mi, gbe beef ẹ wá káfi ròfọ ooo
Ọmọ moti wọ'n, I'm ready for war ooo
Ọmọ ọgbán jorrr, tóbá tìh fẹwá má lọ gọ ooo
(Yepa)
Aimọye àsèjẹ torí dollar dollar
Ẹdá kàn tiraka nìh, Olúwa lóun shọlá shọlá
Ẹní bá robi sími kòní dọlá dọlá
Re mi mi, re re mi re, do mi SoLa SoLa
I got scared really ohhh, not getting the dough
Sometimes high, and sometimes I get really low
Workaholic, lọmọ àwọn kan ma ń pèmí n Kiriyó
Wọ'ní kòmọ oun tókàn bíi ọmọ Naija tóùn lala Lee mihho
Pesin wey dey find honey no dey get horny
Billion dollar dream, but me no get money
No matter how e dark, we go still get morning
Wọ lókàn dẹmọ nìh, iihhhshe, Phakeeee tẹmọ nìh
Ọyẹ lè mú oo, but sun go rise
Garri go turn to rice
Fire go burn the ice
Life may be cold, padi life oo nice
Ọmọ ọlẹ ń fantasize, pàdí go pay the price
Ọmọ ìyá mi, dreams mi loun tìmí, nil dúró tìmí
Feel me, no feel me(Ahh), me be no timid
Elè push battle sími buh give me no limits
U fit frown wen u see me, kiishe bitchiii ló bími
Alhamdulillah fún àwọn nights tá sọ
Far to the days and to the nights tí aà sọ
Though I walk through the valley, **** fear no storm
Óshì waní road, wèrè lọmọ yen lootọ
Ahhh, ehhhi!
Ọkẹrẹ gorí ìrókò ó fún ọdẹ ń shenking
Wón wonder pé kíló kàn ókan decking
Who's gonna build all the walls that we recking?
Now ur guys are checking out when we check in
Wúrà tóma dán go catch fire
Sapphire
Mosọ iná di attire
Way to the top, mofẹ fly higher
Àyà mi ń já torí ǹkán pọ tí mo add máyá
Arghh!
Mo shì n'áwon wounds, kọkan tání kòní sann
Shóma gbàmí, àbí òní gbàmí lọrọ tí mo bá ORÍ sọ
Àjẹ ń jà fún ọmọ rẹ, tóbá délé kòní sọ
Óbàmí mín le guide, inelastic collision
Times I can't see the vision, walk bí ẹni tí ó ní mission
Dream tinnn dabi delusion, soldier tinnn lack ammunition
Time to make the decision, shóma like evolution
Orí ń crave revolution, kọmọ pákó dii golden son
Written by: Philip Ayomide Akeju
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...