Credits
PERFORMING ARTISTS
Niniola
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Niniola Apata
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
ODH
Producer
Songteksten
[Intro]
Nini de o
Ọmọ Apata-Ayeraye
[Verse 1]
T'ọmọ tuntun jojolo ba de (Jojolo ba de)
Nnkan ayọ tuntun de o e
Bọ ṣe n ṣ'aye rẹ lọ ko kan aye (Ko kan aye)
Jijẹ-mimu fun ẹ ko ma ni le
Orekelẹwa my dear mi
Iroyin ayọ ko le sun mi
[PreChorus]
Ki ire ma parada, ma parada di ibi
Ki ire ma sọ pe no, ma sọ pe no s'emi
Ki ire ma parada, ma parada di ibi
Ki ire ma sọ pe no, ma sọ pe no s'emi
[Chorus]
Mo ri aanu rẹ o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ
Oun lo ni ki n ma ṣe foya o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ gidi gan-an
[Verse 2]
Ọlọrun bukun, bukun mi plenty
Iṣẹ kekerẹ, k'owo wa plenty
Sara po mi
I want to tọju my mummy
But if you no get money
You no be somebody
[PreChorus]
Ki ire ma parada, ma parada di ibi
Ki ire ma sọ pe no, ma sọ pe no s'emi
Ki ire ma parada ma parada di ibi
Ki ire ma sọ pe no e, ma sọ pe no s'emi
[Chorus]
Mo ri aanu rẹ o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ
Oun lo ni ki n ma ṣe foya o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ gidi gan-an
[Verse 3]
It's left for you to work very hard
Aderikogi before all na custard
My prayer must surely be answered
Ko ri bẹẹ, ko wa bẹẹ, ko lọ bẹẹ, ko jẹ bẹẹ
[Verse 4]
K'awọ rẹ soke
P'orukọ Jah Jehovah l'ẹẹmeje
Terry Apala, Niniola we dey pray
God, I'm grateful na you I go praise
Come on, (Oh oh Ọlọrun)
[Chorus]
Mo ri aanu rẹ o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ
Oun lo ni ki n ma ṣe foya o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ gidi gan-an
Mo ri aanu rẹ o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ
Oun lo ni ki n ma ṣe foya o
Ọkan mi balẹ
Mo ri iṣẹ ọwọ rẹ o
Ọkan mi balẹ gidi gan-an
[Verse 5]
Mo fẹ tọju mummy mi
Mo fe tọju mummy mi
Iṣẹ kekerẹ k'owo wa plenty
Written by: Niniola Apata