Letra

(Lilu) (Shoka lo ṣe beats) Shoka lolu beat oh Ika producer carry me trabaye o Orin n bẹ niku mi, anjọnu olorin, Ọmọlalọmi Akerin o Them call me Portable Baby oh Turn up, shaku-shaku Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan Moya tete ya danu o, kan to para pẹlu Jagamu o K'ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o Na mi get Zazu, are you mad on something o? I'm a bigi man, ṣe mo jọ talaka o? Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o Turn up, shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o If you no get money (clear) Ko ya tete ya danu o (clear) Olowo ni ṣ'ọrẹ olowo (clear) Olowo la wọn ọrẹ mi (clear) Isọkusọ mapa data (clear) Ṣọ'ra fun awọn ripper (clear) If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear) Clear, clear, clear, clear, clear, clear Clear Emi Ika o, baba Ika o, eyan Ika o, wu wa Ika o Ika o le wo oju ka o (clear) Ika n bẹru ika o (clear) Ika o le dẹmọ fun ika o (clear) Ika ranju mọ ika o (clear) Ọmọ oro mi, know person o (clear) If you trust person o (clear) You go learn lesson o (clear) Ọmọ better, more blessing o, ma lọ dapọ mọ ero Dapọ abi ko danu o Ọrẹ star, star ni o, gbogbo nkan by lucky ni o If you no get money (clear) Ko ya tete ya danu o (clear) Olowo ni ṣ'ọrẹ olowo (clear) Olowo la wọn ọrẹ mi (clear) Isọkusọ mapa data (clear) Ṣọ'ra fun awọn ripper (clear) If you no get money, ko ya, ko ya danu o (lilu) Clear, clear, clear, clear, clear, clear If you no get money, ko ya, ko ya danu o (clear) Wọn sare lọ, unfollow wa o tori wọn ri jẹ lara wa mọ Ko si yẹn mọ, ọmọ ologo ti gbera tan Moya tete ya danu o, kan to para pẹlu Jagamu o K'ọn ma lọ ka mi mọ, mo ya tete sapa mọ o Na me get Zazu, are you mad on something o? I'm a bigi man, ṣe mo jọ talaka o? Ọmọlalọmi Akerin o, them call me Portable Baby o Turn up, shaku-shaku o, emi ni wèrè olorin o (lilu)
Writer(s): Mudashiru Olajide, Habeeb Okikiola Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out