Créditos
INTERPRETAÇÃO
EmmaOMG
Regência (orquestra)
SoundMindPro
Vocal de apoio
Goodness Patrick Adeosun
Vocal de apoio
Tobi Emmanuel Osinaya
Vocal de apoio
Bajulaye Victor Oluwaseun
Vocal de apoio
Ayomiotitan Olateju
Baixo
Love Abolade
Vocal de apoio
Cynthia Princewill Alfred
Vocal de apoio
Dan Edmund
Guitarra rítmica
Ojo Gloria
Vocal de apoio
Esther Cecilia James
Vocal de apoio
Ajayi Joseph Oluwaseun
Piano
Olamide Adeleye
Teclados
Rhema Joseph Ahons
Vocal de apoio
Yimika Akinola
Órgão
Daniel Alan
Coral
Olakanye Iyanuoluwa Omobolanle
Coral
Eyinolu Opeyemi Ayomide
Coral
Michelle Obilor
Coral
Sarah Alasan
Coral
Ossai Chioma
Coral
Kegbeyale Olubukola
Coral
Iyanuoluwa Christiana Oke
Coral
Oluwasholafunmi Favour Rapheal
Coral
Omolara Oladimeji
Coral
Georgina Inemesit Eka
Coral
Dolapo Oladele Awodele
Coral
Esther Olorunfemi
Coral
Olaniyi Temitope Mary
Coral
Adeosun Oluwatoyin Esther
Coral
Olami Deborah Olusola
Coral
Hassan bukola
Coral
Woye Itimi Enifome Jennifer
Coral
Chioma Odimegwu
Coral
Daibiloloari Young
Coral
Oladokun Abosede Deborah
Coral
Oreoluwa Oyesagba
Coral
Loveth Oghenekevwe
Coral
Racheal Igbarie
Coral
Damilola Esther Dada
Coral
Deborah Nofiu
Coral
TeminiJesu Rebecca Obe
Coral
Akinwasola Anuoluwapo
Coral
Blessing Ituen
Coral
Tèmilolúwa Akínwándé
Coral
Idowu Daniel
Coral
Olamide Oyesagba
Coral
Anuoluwapo Maxwell Amusu
Coral
Omenogor Daniel
Coral
Timileyin Akoore
Coral
Adeeyo Timilehin
Coral
Oluwafemi Gold Olayode
Coral
Samuel Dare Ojuotimi
Coral
Aiyepada Gabriel
Coral
Dada Joshua
Coral
Toby Davyd
Coral
Omotoye Ayooluwa
Coral
John Sounds
Coral
John Osemudiamen
Coral
Tomiwa Adeshina Taiwo
Coral
AYOMIDE DAVID KEHINDE
Coral
Awopeju Olakunle
Orquestra
COMPOSIÇÃO E LETRA
Pelumi Deborah
Composição
Emmanuel Edunjobi
Composição
Bakare Boluwatife Oluwatobi
Composição
EmmaOMG
Arranjos
PRODUÇÃO E ENGENHARIA
EmmaOMG
Produção
SoundMindPro
Engenharia (mixagem)
Letra
Oluwa tobi ni Sioni
O si j\'oba lori orile-ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
E ni pe gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin
E ti tobi to o
Jesu
Eh eh
Eh eh (Make some noise)
Eh eh
Eh eh
Eh eh
Eh eh
Eh eh
Eh eh
Eh eh
Ani Oluwa tobi ni Sioni
O si j\'oba lori orile-ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti o si ni eru
Shout hallelujah
\'Tori gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun na n s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re o
E ti tobi to o
Jesu
Won ni E ti tobi to o
Oooo
Oluwa wa
E ti tobi to o
Jesu
Won ni e ti tobi to ooo
Oooo
Ooo Oluwa wa o
E ti tobi to o
Jesu
Ani gbogbo aye n wariri o
Ni oruko re
Won n k\'orin yeh
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun na n s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re o
E ti tobi to o
Jesu
Won ni E ti tobi to o eh
Ooooo
Oluwa wa o
E ti tobi to o
Jesu
Won ni e ti tobi to o
Ooooo
Ooo Oluwa wa o
E ti tobi to o
Jesu
Awon oke nla nla won f\'oribale
Tori Iwo ni ogo ati ola
Ju oke nla ikogun won ni lo
E ti tobi to o
Jesu
Iwo ti Olorun
Ji dide kuro ninu oku
Lati gba wa kuro
Ninu ibinu ti\'n bo o
Eti tobi to o
Jesu
Iwo Oluwa Olorun
To n gbe laarin awon Kerubu
T\'o po ni ipa ati agbara o
E ti tobi to o
Jesu
Ani gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin yeh
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun na n s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re o
E ti tobi to o (Ladies and gentlemen)
Jesu (Welcome Pelumi Deborah)
Eeeeeeh
E ti tobi to Jesu
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun n soro ogo Olorun
Ofurufu n fi ise re han
Ojo de ojo n f\'ohun
Oru de oru n fi imo han oooo
E ti tobi to o (Jesu Jesu oooo)
Jesu
Ko si ibi kan tabi ede kan
N\'ibi ti a ko ti gbo iro wan
Iro won la aye ja aaaaah
E ti tobi to o (Jesu Jesu Jesu o)
Jesu
Mo le ko gbogbo eyin mi si Inu apere re
Tori o to gb\'ojule
O to f\'eyinti
O to f\'arati Olodumare
E ti tobi to o
Jesu
Okun ri o o sa
Jodani ri o o pada s\'eyin
Oke kekeke o je duro
Niwaju Olodumare
E ti tobi to o (Apata Idigbolu)
Jesu (Apata Idigbolu)
Apata ayeraye ibi isadi mi
Eni ti mo f\'eyin ti
Ti ko le wo
Ti ko le si
Ti ko le yi ni\'po pada
E ti tobi to o
Jesu
\'Torina
Gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun na n s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re
E ti tobi to o
Jesu
Won ni e ti tobi to o
Oooo
Oluwa wa
E ti tobi to o
Jesu
Won ni e ti tobi to o
Ooooo
Oluwa wa
E ti tobi to o
Jesu
Bibeli ni ti Oluwa ni ile ati ekun re
Aiye, ati awon ti o tedo si Inu re
Nitori ti o fi idi re sole lori okun
Osi gbekale lori awon isan-omi
Tani yio gori oke Oluwa lo?
Tabi tani yio duro nibi mimo re?
Eniti o ni owo mimo ati aya funfun
Eniti ko gbe okan re ka\'le soke si asan
Ti ko si bura etan
Oun ni yio ri ibukun gba
Ati ododo l\'owo Olorun igbala re
Eyi ni iran awon ti n se aferi re
Ti n se aferi re Olorun Jakobu
E gbe ori yin s\'oke, eyin enu-ona
Ki a si gbe\'yin s\'oke, eyin ilekun ayeraye
Ki Oba ogo ki o wole wa
Tani Oba ogo?
Oluwa ti o le ti o l\'agbara
Oluwa ti o l\'agbara ni ogun
E gbe ori yin s\'oke, eyin enu-ona
Ki a si gbe\'yin s\'oke, eyin ilekun ayeraye
Ki Oba ogo ki o wole wa
Tani Oba ogo?
Oluwa Olorun awon omo ogun
Oun na ni Oba ogo (Jeeeesu)
Ladies and Gentlemen
Welcome Minister BBO
Eni ti ite re ki si
Eni ti ite re ki sa
Oloruko ape-ri-iye
Ar\'aye-r\'orun leekan soso
E ti tobi to o
Olorun majemu (Jesu)
Araye n bo o
Ara orun n bo o
Apebo ni o
Olodu Omo Are
Oloruko ape ri iyanu
E ti tobi to o (eeeeeeeeh)
Jesu
Iwo to koja riri tan
See finish ko si l\'oro re o
Iranlowo eni ti o l\'eyan
Oba awon oba Olorun mi
E ti tobi to o (yeeeeh)
Jesu
Olorun to n da ase pa
Oo gba\'se l\'owo enikeni ko to p\'ase
Ta lo dabi ire ninu agbara
Olorun majemu
Eti tobi to o (Eeeehhh)
Jesu
Iwo to ma n tun ori alaisuwon se
Pelu owo agbara
O ro e l\'orun, ko ni e l\'ara
Irorun lo ba de l\'odo re Oko mi
E ti tobi to o (Yeeeh)
Jesu
O da aye s\'ori omi, omi o je gbe\'le aye lo
Tani o to ri e tan Olorun majemu
Iranlowo eni ti o l\'eyan, oko mi
E ti tobi to o
Jesu
Olorun ti o ki n rin irin idoti
Olorun ta o le fi iwosi re l\'ara
Oluwa Oluwa wa o
Olorun majemu, Olorun mi
E ti tobi to o
Jesu
Ani gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin
E ti tobi to o
Jesu
Awon orun na n s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re oooo
E ti tobi to o
Jesu
Won ni pe
Won ni pe
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (E ba mi o)
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (See see see)
Let me teach you the Juba dance
Eeeh
Eeeh
Eeeh
Eeeh
Eeeh
Oya e ba mi o
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (E ba mi e ba mi e ba mi)
E ba mi juba f\'ajunilo (E ba n gb\'osuba)
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo (Awon agbagba)
E ba mi juba f\'ajunilo (merinlelogun won n ju\'ba)
Won n ju\'ba (E maa ju\'ba lo)
E ba mi juba f\'ajunilo (E ba wa ju\'ba e ba mi ba mi o)
E ba mi juba (Eh) f\'ajunilo
Oba to n be lori ite titilai (E ba n gb\'osuba f\'ajunilo)
A da\'ra po mo awon orun lati keee (E ba mi juba f\'ajunilo)
Mimo mimo mimo
E ba mi juba f\'ajunilo (Si Oluwa Olorun Olodumare)
E ba mi juba f\'ajunilo (A si ite wa le\'le)
A si aye wa le\'le (E ba n gb\'osuba f\'ajunilo)
A gbe s\'ori ese re ooooo (E ba mi juba f\'ajunilo)
Jesu oooo
E ba mi juba f\'ajunilo
BBO ju\'ba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (E ju\'ba f\'olojukan)
Ti n wo egbegberun eniyan (E ba n gb\'osuba f\'ajunilo)
E ju\'ba f\'oloruko ape ri iye ooo (E ba mi juba f\'ajunilo)
E ba mi juba f\'ajunilo (A ju\'ba fun e Mogaji awon alagbara)
E ba mi juba f\'ajunilo (A ju\'ba re oba to n so egan d\'ogo)
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (Eh eh eh eh eh eeeeeh)
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (Aju\'nilo o)
E ba n gb\'osuba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo
E ba mi juba f\'ajunilo (tori pe)
O wa pel\'awon
Ero mimo l\'ona (O si je o)
O si je
Imole won
L\'osan l\'or
Ani O wa pel\'awon
Ero mimo
L\'ona o
O si je
Imole won
L\'osan l\'oru
Gbogbo aye n wariri
Ni oruko re
Won n k\'orin, (e ti tobi to o)
E ti tobi to o
Jesu
Somebody shout Hallelujah
Thank You jesus
Thank You jesus
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah thank You
Thank you Jesus
Awon orun na s\'eleri
Won n f\'oribale
Niwaju ite re o
E ti tobi to o
Jesu
Thank You Jesus
Hallelujah!
Written by: Bakare Boluwatife Oluwatobi, Emmanuel Edunjobi, Pelumi Deborah