Vídeo de música

Destacado em

Créditos

PERFORMING ARTISTS
Oriyomi Kehinde Sanni
Oriyomi Kehinde Sanni
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oriyomi Kehinde Sanni
Oriyomi Kehinde Sanni
Songwriter

Letra

Jerryson production Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Oni lari ola nbo, kamura k'ola tole Oun toni kafun toni, ola a beere fun tie Loju eda onajin, won o mo poju lopesi Ola ojin mo rara, k'ato w'eyin ojo a pe O ngbero p'ofese igbiyanju ko d'eyan nla Ŏtètè ya mura kose lasiko ni Kia Ma f'akoko dola, dola, dola Ma f'akoko dola, o je gbegbese kotope Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Naam Ije omokunrin laye, seri latigba tontibi Lati omo odun kan si mewa, yio wa leni obi nto Odun mewa si 20, oge nioma fiyen se Konironu jupe kora bata pelu awon aso Lati ogun odun si thirty loye kotile daduro Kotile nise lowo tio fi bora e dede Ko feyawo kobimo, oye kotile d'ayegbe Biotete seyen tobaya, a full at fourty niaje Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa K'omokunrin o mura, koma f'akoko dale mo Ogoji odun si fifty kotiseto f'ale Koma f'agba f'ewu ori deni to ntile kiri Agbantara bodale oye kotile maje Awon ise osan e totise nigba odo laye Mowa latise nikilo fun awon odo kongbo Pe'gba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa From 18 si 23 t'omobinrin ngbonju Oge sise ma niopo, koniro pegba yen ntan Attention toni tio poju, lori okunrin ni Eyi tobani obi tio b gba gbenren rara Won o ni fun laye komadi poma fa iyonu 23 to 25 koti leyan tiafe Ije omobinrin delicate toba nfakoko sere Toba koja 26 to sunmo 30 penren Afaimo koma lo lele abi kofeyan tobari Omobinrin olomoge nimowa kiloyi fun Pegba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Igba ara lanbura, lanbura, lanbura Etò l'oro aye gba eje kafeto setiwa Ireti ayo ayemi jeko tetede, eyi toku loromi banse koya Ireti ayo ayemi jeko tetede, eyi toku loromi banse koya Eniyan loleso funwa wipe otipoju Eda tobale tiju gan o tun nile bere P'ogbakan lana o kan Olohun, yio se toni Obeere lola o nilara, t'olohun niyen Motete yayo s'olohun tonse temi Mobere anu e totise, mofe koposi Eyi to tunku loromi banse kiya Eyi to tunku loromi banje koya Ireti ayo ayemi jeko tetede, eyi toku loromi banse koya Aisan to ntini lojuwa ti kiibewa je o Sungbon toba jeyo lojokan, yio ba ayo je Setunmo p'arun owo wa fun omo eda S'aye teniyan to lola, ton ni small body Teniyan tio r'owo jeun nsanra juwon Olohun lo cleaner re funwon, pa isoro won re Kotun lo cleanser yen funwon, ko pare kiya Eyi tobaku lorowa, bawa se koya Ireti ayo ayemi jeko tetede, eyi toku loromi banse koya Dukiya mi timo kojo, komase dofo Ise timowa lori e, komase tuka Toba wa pada dowo mi, koma pada bo Dakun fimise apejuwe aladura kan ni T'adua tigba kotose debi amin Robbi inni lima anzalta ilayya Min khaerin faqeerun bami s'amin Min khaerin faqeerun ebami s'amin Ireti ayo ayemi jeko tetede, eyi toku loromi banse koya Abinueni yan're, o falaroka se bestie Abosi d'egbe, won f'onilara se pressy Abinueni yan're, o falaroka se bestie Won sabosi d'egbe, won f'onilara se pressy Awon oloju aye ore Gbogbo won polo biba Asiri wa tatibo, baso funwon won a titu Koma da funwa non ngbero Onda won nro kobaje Ola inukan timing Ama komiyo jare Kaka konso bi asewa, iro nonpa nipa wa Tasiri wa ba tibo, untoba wuyin nieso Abinueni yan're, o falaroka se bestie Won sabosi d'egbe, won f'onilara se pressy Etekete nitota, ogbon lonso won dode Ote tonro pontipa, kokoro wa tomasi Base nlayo ta nyayo, ibanuje ni lodo won Oun tole je kon happy, nipe konri pobaje Kolebaje esatimo, awa o ronu kobaje Ounkoun tongbero siwa, koma je tiwon ni Abinueni yan're, o falaroka se bestie Won sabosi d'egbe, won f'onilara se pressy Matakomi alatako, eni engbe subu tiko wo Akoba loku te o mawa, atise saraa alakoba F'onibara to npariwo, akoba atadaba Adaba atakoba, yato sipe iyawo nkobo Ao raye f'akoba, afidera ni ojo gbogbo Eni laya to ngbebo, trailer ni o fun nisinmi Abinueni yan're, o falaroka se bestie Won sabosi d'egbe, won f'onilara se pressy Seremi mo npoluwa Ontete je kiya Mo npoluwa, ontete je kiya Beni mo nfejo sun Ongbeja funmi gan Mo nrin nile, onfiso bami lo Beni mo nfo loke, mio mani jabo Mo nbelohu, ontete se kiya Aaaah ah ah, ontete se kiya
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out