Music Video

Music Video

Lyrics

Ẹma je o já bọ lẹ o
Bi ijo ba ti ya ẹ jẹ á jó,olu ayé fuji ló ń bọ'
Ni se nà mọ Ayinde Wasiu sọ fún wọn
Wan tun ń na,wọn n k'owó lè
Ni se nà mọ Ayinde Wasiu sọ fún wọn
Wan tun ń na,wọn n k'owó lè
Ni se nà mọ Ayinde Wasiu sọ fún wọn
Kan tun ń na,wọn ń k'owó lè
Àwa sa la ní lẹ yí o
Ogbọ bi ọba fuji ṣe ń bọ
Mọ lọ gbọ' bi ọba fuji ṣe ń bọ
Àwa sa la ní lẹ yí o
Àbí o gbọ ọrọ mí gan
Gbangba dẹkùn ó, kedere bẹẹ wò
Gbangba dẹkùn, kedere bẹẹ wò
Gbangba dẹkùn ó, kedere bẹẹ wò
Gbangba dẹkùn, kedere bẹẹ wò
Ọ'rọ' yí wa di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Ọrọ yí wa di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Eré lon lọ (eré lon lọ)
Eré lon lọ o (eré lon lọ)
O di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Ma wò mí o, ma wo mi (ma wo mi)
Ma wò mí o, ma wo mi (ma wo mi)
Ma wò mí o, ma wo mi (ma wo mi)
Ma wò mí o, ma wo mi (ma wo mi)
Ma wò mí o, ma wo mi (ma wo mi)
Common look (ma wo mi)
Common look (ma wo mi)
Common look (ma wo mi)
Common look (ma wo mi)
Common look (ma wo mi)
Okay look me (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Mo ni ma wò mí o (ma wo mi)
Ìgbà to de èkó, lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ìgbà to de èkó, lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ìgbà to de èkó,lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ọ'rọ' yí wa di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Ó di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Ó di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ma wò mí o (ma wo mi)
Ìgbà to de èkó, lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
To de èkó, lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
To de èkó o, lo mọ ẹyọ (lo mọ ẹyọ)
Ọ'rọ' yí wa di Salimutisi ó, ẹsin burúkú
Ijo l'ẹsẹ, eré lon lọ
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...