album cover

Bá’núsọ

34,324Alternative Folk2018
album cover
00:00
00:10
00:25
00:40
00:45
00:55
01:05
01:15
01:20
01:30
01:40
01:55
03:15
00:00
03:24
Past 7 Days
Bá’núsọ was discovered most frequently at around 45 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Verse 1]
Abẹrẹ a lọ, abẹrẹ a lọ
Kọna okun o to di o
A o ni de ba wọn, a o ni de ba wọn
Ẹni ba ni a ma a de o
[Chorus]
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
[Verse 2]
Omije a gbẹ, omije a gbẹ
Ibanujẹ a dẹrin o
Ẹni a fẹ, ẹni a fẹ la mọ o
A o mẹni to fẹni o
[Chorus]
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
[Verse 3]
Ẹni ba ma b'Eṣu jẹun
Ṣibii rẹ a gun gan-an
Ẹni o mọwa hu, o maa tẹ
Oṣelu ma lo laye o
[Chorus]
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
[Verse 4]
Ẹyin ara, ẹ wa gbọ o
Ọrọ kan n ṣe hunrun-hunrun ninu mi
Ṣe ki n sọ ọ, ki n sọ ọ?
Ka banusọ banusọ
N o ni beniyan sọ
[Chorus]
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
Banusọ, banusọ
Ma beniyan sọ
Written by: Olawale Olofo'ro

Shazam Footer

Select language:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

Follow Us

Loading...