Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Dr. Victor Olaiya
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Dr. Victor Olaiya
Composer
Lyrics
To ba fe l'owo ko ma se fo'le, fo'le o (ewa)
To ba fe l'owo ko ma se fo'le (ewa), fo'le o (ewa) fo'le
So gboro mi (ewa), ko ma se ja' le ore o (ewa)
Kere kere kere o (ewa), kere o kere o (ewa)
L'okunrin l'obirin (ewa), l'omode l'agba o (ewa)
L'okunrin l'obirin (ewa), l'omode l'agba (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa)
Ohun s'ewa
To ba fe l'owo ko ma se fo'le, fo'le o (ewa)
To ba fe l'owo ko ma se fo'le (ewa), fo'le o (ewa) fo'le
So gboro mi (ewa), ko ma se ja' le ore o (ewa)
Kere kere kere o (ewa), kere o kere o (ewa)
L'okunrin l'obirin (ewa), l'omode l'agba o (ewa)
L'omode l'agba (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa)
Ohun s'ewa (ewa), ohun t'ewa (ewa ewa)
Written by: Victor Bimbola Olaiya