Lyrics

[Intro]
Ẹ jẹ ka fi asikiri kọra wa n kewu (Kewu)
Ìbà ẹyin aliulamọu warasatul anbiyai (Anbiyai)
Mọ júbà ẹyin aliulamọu warasatul anbiya (Anbiyai)
Ẹyin làròlé bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)
Ẹyin làròlé bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)
Ẹyinjú Anọbi, bàbá Fatimo mi Muhammo (Muhammo)
[Verse 1]
Wa Yarobi Ansurini wa Nasira Nasisa bijahi Rosulu'llah Wa Musa kasa Yisa
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
Wa Musa kasa Yisa (Wa Musa kasa Yisa)
[Verse 2]
Ọlá Ọlọrun Ọba mí pọ, bọlá Alahurabi tí tóbi tó
O ṣọlá Musa, ọlá Yisa, ó ṣọla Sulaimona
Ó ṣọlá Dauda, Owa ṣọlá anọbi Muhammadu (Sala Allahu Alei Wa Sallam)
Wali Musitafa Akẹhinde gbẹgbọn o (Sala Allahu Alei Wa Sallam)
Baba Fatimo (Sala Allahu Alei Wa Sallam)
[Verse 3]
Olúwa, ó sá ti mọ pé n lẹnìkan Olúwa o
Ó kúkú ti mọ pe n lọnà méjì
Lo fí gbe ere fuji yí lé mi lọwọ
Ma ṣe jere naa ó bajẹ mọ mí lọwọ (Àmín oga wá)
[Verse 4]
Ẹyin eeyan mí ẹ jẹ a da waka fun Muhammo onisẹ ńlá
Rosulu'llahi onisẹ ńlá
Mo lẹyin eeyan mi
Ẹ jẹ a da waka fun Muhammo (Onisẹ ńlá Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Akẹyinde gbẹgbọn baba Fatimo ọrẹ Ọlọhun (Onisẹ ńlá,Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Ikẹ ati ọla ko ma bá nìlú Medina amin (Onisẹ ńlá, Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Oun lẹni ta o ba ó ti gbogbo àyè ń jẹran ẹ ni (Onisẹ ńlá,Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
[Verse 5]
Rọbana rọbali alaiki, Rọbana rọbali alaiki
Najina min sari samani, Najina min sari samani
Wa gina min kasa lamọta watina min kasa adata
Waridọ mọn ana ili'lamoni, Waridọ mọn ana ili'lamoni
[Verse 6]
Sheu Sulemọna Faruk mí, Ali miskin Bi'llahi mi
Ọkọ haja Ramọta Kehinde
Baba Mariam, baba Iradaatulahi
Ẹ ku iṣẹ asikiri fún oniṣẹ ńlá (Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Iná mí Sulemọna mí, Wa inahu Bisimillahi mí amin
Sulemọna ọrẹ Ọlọhun
Mọ kí yin ẹ ku isẹ asikiri
Sheik Isiaka, ọmọ Agbarigidoma pẹlú Maifu Allah
Ẹ ku iṣẹ asikiri fún oniṣẹ ńlá (Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
[Verse 7]
Amir Awolabi Kazeem mi
Sheik Arisukuna Suraju
P'lú C Nureni ẹ má ku isẹ ti asikiri fún oniṣẹ ńlá (Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Isibulahi ni ìjọ wa àti Alfa ńlá
Sheik Atanda Suraju Sanusi
Atanda ọmọ Oko ẹ ku isẹ t'asikiri fún oniṣẹ ńlá (Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
Sheik Sul Kanai nimi àkèrékorò L'Okòkò
E yí to ti da kò ní bajẹ, ẹ kú isẹ asikiri fún oniṣẹ ńlá (Rosulu'llahi onisẹ ńlá)
[Verse 8]
Alubarika mo tọrọ (Alubarika mo tọrọ)
Alubarika mo tọrọ (Alubarika mo tọrọ)
Ẹmi gígùn mo tọrọ (Ẹmi gígùn mo tọrọ)
Àlàáfíà mo tọrọ (Àlàáfíà mo tọrọ)
Àlàáfíà mo tọrọ (Àlàáfíà mo tọrọ)
Àlàáfíà mo tọrọ (Àlàáfíà mo tọrọ)
Ẹmi gígùn mo tọrọ (Ẹmi gígùn mo tọrọ)
Alubarika lo ń wá (Alubarika lo ń wá)
Alubarika lo ń wá (Alubarika lo ń wá)
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...