Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
OgoOluwa Akin-Alade
OgoOluwa Akin-Alade
Electric Bass Guitar
Adaeze Kalu
Adaeze Kalu
Background Vocals
Ifeoluwa Onapajo
Ifeoluwa Onapajo
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Akinade Ibuoye
Akinade Ibuoye
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Olumide "ID Cabasa" Ogunade
Olumide "ID Cabasa" Ogunade
Producer

Lyrics

[Verse 1]
For our family money dey flow well well, enjoyment plenty
And the way our parents dey spend the money, se l'ọn f'ile pọnti
Ohun to ba wu wọn lọ'n ra, our parents dey groove dem just dey ball
Ferrari loni, Ferragamo tomorrow, designer nikan l'ọn wọ
But the children dey suffer, like rats in the gutter
O de ye kẹ ẹ mọ pe person wey dey suffer no get time to care for another
And so the children are fighting, they're fighting each other
Ohun to yẹ ka ba obi wa fa, la n bara wa fa
[Chorus]
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
(Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ)
Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ
Ani wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ, lọ jẹun
[Verse 2]
Crisis happen, the family income drop oh
But, our parents, their flenjour e no stop oh
Pikin wey dey suffer before
Na him dem dey make suffer some more
Wọn ni wọn o le sanwo oṣu, awọn gba estacode
Presidential fleet intact
Allowances intact
Senate budget coded, wọn fẹ ka mọ nnkan tọ'n gba nbẹ
But 8000 no longer fills fuel tank again oh
Awọn o le sacrifice, na we dey bear the pain
[Chorus]
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
(Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ)
Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ
Ani wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ, lọ jẹun
[Verse 3]
Servants, servants, public servants
But it seems like we are your servants
Like you're doing us a favour
But you're getting fat on our labours
Wọn ma le o, awọn ijoye yii maa le o
Ajantiele, ajantiele
Yoo ma lẹyin, ọrọ yii o maa lẹyin, ọrọ yii o maa lẹyin
Ajantiele, ajantiele lele
[Chorus]
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
Wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki, wọnbiliki wọbia
(Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ)
Wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ
Ani wọn n gbọmọ adiyẹ lọwọ iku
O ni wọn o jẹ koun lọ akitan lọ jẹ, lọ jẹun
Written by: Akinade Ibuoye, Id Cabasa
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...