Credits
PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
Performer
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Drums
COMPOSITION & LYRICS
Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe
Songwriter
Lyrics
Àwọn ọ̀dọ́ ìsẹ̀yín
(Kì ń f’owó ṣe ohun tó da ó)
Àwọn ọ̀dọ́ ìsẹ̀yín
(Kì ń f’owó ṣe ohun tó da ó)
Mo tún dé bí n ṣe ń dé
K1 De Ultimate Arábámbí
Àní àwọn ọ̀dọ̀ ìsẹ̀yín
Kì ń f’owó ṣe ohun tó da o
Àwọn ọmọdé ìsẹ̀yín
(Ti ń f’owó ṣehun tó da o)
Àní tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀ ní àwọn kan ma ń d’áṣà
(Pé owó tí ọmọdé bá kọ́kọ́ rí)
(Àkàrà ní fi ń jẹ)
Mo ní tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀ ní àwọn kan ma ń d’áṣà
(Pé owó tí ọmọdé bá kọ́kọ́ rí)
(Àkàrà ló fi ń jẹ)
Má bá wọn d’áṣà irú ẹ̀
Ìsẹ̀yín mà ti yàtọ̀
Estimate lóríṣíríṣi ni wọ́n ń f’owó dá sílẹ̀
Ilé ńlá ńlá bíí I skyscraper
Exclusive properties ní Ìkẹjà GRA
Ìkòyí, Banana, bẹ bá kọjá dé Lekki
Tó bá máa jẹ́ farmer Àgbẹ̀lọba
Animal Ranch ìyẹ́n wá pọ̀ Yanturẹrẹrẹ
Àní àwọn ọ̀dọ́ Ìsẹ̀yín
(Tí n f’owó ṣe ohun tó da o)
Gbogbo àwọn ọmọ kékèké
Tí Ọlọ́hun Ọba fi dùn wá nínú
A ò ní fi wọ́n ṣe àwátì
Bó bá wu ọlá Ọlọ́hun Ọba Àmín
T’Hausa ti Ibo tó fi dé orí Yoruba wá
Má a gbọ́ bí n ṣe ń wí
Ọláńrewájú Ìlàrí
Henry ọmọ Òbíṣẹsan l’ókè Ìbàdàn
Ní Olúyọ̀lé ilé
Olórí gbogbo kọ́lé kọ́lé nílẹ̀ yìí
Ìlàrí, gbogbo iṣẹ́ ẹ ò ní dojúrú
O ò gbọ́ bí mo ṣe ń wí
Abu mi Abel mi Ẹgbàrin
Developer tó ń kọ́lé ńlá ńlá
Ṣọlápé ọmọ t’Ògúnbà
Emmabaddy aláṣẹ baddy Auto
Àti Barrister lawyer mi Táíwò Ṣọ̀tẹ̀ mi
Ègbé Búrùjí
Ara wọn ni Chief Tọ́mọrí ọmọ Williams
Ààrẹ Oníkòyí gbogbo Yorùbá Land
Èèyàn Fuad ọmọ ọlọ́tọ̀
Àti Àlàbí Akínṣìkù ọkọ Naimo
Ṣe ìtọ́jú Kúnlé Oòduà mi
Àwọn ọ̀dọ́ ìsẹ̀yín
(Ti ń f’owó ṣe ohun tó da o)
Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni
(Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni)
Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni
(Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni)
(Ìwọ náà kọ́ Ọlọ́hun Ọba mà mà ni)
(Ajíbọ́lá ọmọ Bisiriyu)
(Aláṣẹ Direct Construction)
(Ó ń kọ ilé, ó ń tà ilé)
(Ọmọ Alhaji Monsuru)
(Ọmọ ọmọ Alhaja ní Oshodi)
(Ọmọ ọmọ Mummy aláṣọ)
Ajíbọ́lá ọmọ Bisiriyu
Máa gbọ́ bí n ṣe ń wí
Nínú gbogbo kọ́lé kọ́lé
Tì ẹ́ yàtọ̀
Mini Estate, super Estate
Lóríṣiríṣi o, tó fi dé Ìkòyí dé Banana
Ọkọ Olúwatósìn mi ọlá bàbá Farhan
Bàbá Faiza Bisiriyu Ajíbọ́lá
Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni
(Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni)
Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni
(Bí wọ́n ń pé ìwọ ni ìwọ ni ìwọ ni)
(Ìwọ náà kọ́ Ọlọ́hun Ọba mà mà ni)
(Ajíbọ́lá ọmọ Bisiriyu)
(Aláṣẹ Direct Construction)
(Ó ń kọ ilé, ó ń tà ilé)
(Ọmọ Alhaji Monsuru)
(Ọmọ ọmọ Alhaja ní Oshodi)
(Ọmọ ọmọ Mummy aláṣọ)
Ilé e durability ṣá ni tì ẹ
Ọ̀rẹ́ ti Táyé onílogbò
Ìyẹn òyìnbó onímọ́tò
Ó tún ń kọ́ ilé ńlá ńlá
Ọ̀rẹ́ Chief Habeeb mi Okùnọlá
Àkọ́sìn gbogbo yorùbá
Àwọn ọmọ alálùbáríkà
Ẹ ẹ̀ ní jábọ́ mọ́ wa lọ́wọ́
Ajíbọ́lá ọ̀rẹ́ ẹ ti Warees mi
Ọmọ Aro Lambo yìí o ṣé
Awo Prince Ọmọ́gbọ́láhàn mi
Ọmọ Anímáshaun
Ọmọ Aláyélúwà baàmi
Ìṣọ̀lá mi Kamoru Adé á pẹ́ lórí
Ọlọ́jà nílùú Ẹ̀pẹ́
Gbọ́láhàn ọkọ Adùnọlá baby
Adùn ní Ìjẹ̀bú Ayépé
Máa gbọ́ bí mo ṣe ń wí
Ṣíwájú Jídé ọmọ Fádéyibí
Olúwahẹ̀ yìí o ṣé
Ọ̀rẹ́ ẹ Jíbọ́lá Bisiriyu
Ọ̀rẹ́ Dọlápọ̀ mo kí ẹ Apopo Balógun
Ní Ìjẹ̀bú Òde ọkọ Kúnbi Baby
Bàbá Èjìrẹ́ ọmọ méjì
Ìyẹn òyìnbó ní computer
Ní Computer Village
Ajé á wọ igbá ẹ Àmín o
Ọ̀rẹ́ Bídèmí mi Rufai
Ṣèyí ọmọ t’Ògúǹdé
Ìyẹn Sànmọ̀rí Èkó
Àdúà á máa gba gbogbo yín ni mo kí
Ajíbọ́lá Bisiriyu
(Ó ń kọ́’lé, ó ń ta’lé)
Ajíbọ́lá Bisiriyu
(Ó ń kọ́lé, ó ń ta’lé)
Ilé aláràǹbarà
(Ó ń kọ́ lé ó ń ta’lé)
Ẹ bá mi kí ọkọ Tósìn
(Ó ń kọ́’lé, ó ń ta’lé)
Ọmọ ọmọ mummy Aláṣọ
(Ó ń kọ́ lé ó ń ta’lé)
Jíbọ́lá Bisiriyu
(Ó ń kọ́’lé, ó ń ta’lé)
Ogbons máa gbọ́ bí n ṣe ń wí
Ní Chicago gbogbo ara ni mo fi kí ẹ
Ọmọ Ṣọ̀tẹ̀márù ní ìlú Ìjẹ̀bú Òde
Ẹbí Azeez mi Ògèdèǹgbé
Èèyàn Saheed **** mi o ṣeun
Máa gbọ́ bí mo ṣe ń wí
Abbey Àlàmú òyìnbó onímọ́tò mi
Awo ti onímọlẹ̀ ní Ìkòròdú o
Ẹní f’owó ṣe ohun tó da o
(Àwọn lọmọ olóore)
TJ ọmọ Balógun máa gbọ́
(Àwọn lọmọ olóore)
Ẹní f’owó ṣe ohun tó da sẹ́
(Àwọn lọmọ olóore)
Ìyà kan ò gbọdọ̀ jẹ́ o
(Àwọn lọmọ olóore)
Àwọn ọmọ ṣiṣẹ́ ṣiṣẹ́
(Àwọn lọmọ olóore)
Ẹ̀sẹ̀ kọ́ ni tí wọ́n bá jẹ ìgbádùn
(Àwọn lọmọ olóore)
Bó ṣe Èkó bó ṣe Ìbàdàn
(Àwọn lọmọ olóore)
Bó ṣe Abẹ́òkúta bó ṣe Ìjẹ̀bú òde o
(Àwọn lọmọ olóore)
Ibi yòówù tẹ́ ẹ bá wà ní ìlú Òyìnbó kárí àgbáyé
(Àwọn lọmọ olóore)
Àánú Ọlọ́hun Ọba á máa bá yín gbé
(Àwọn lọmọ olóore)
Saro ọmọ Lukumonu
Yọ̀mí ọmọ Ṣóyọyè ẹ máa gbọ́
Ẹ sìn mí lọ sí Mushin Àyìndé Adé
Mò ń relé Yusufu Àyìnlá adé
Àyìnlá Babátúndé
Ọmọ Gbọ́njúbọ́lá Alhaja mi Àyìnlá
Ọkọ Fadéṣẹwà gbogbo ara ni mo fi kí ẹ
Aláṣẹ extra quality plywood
Ìlúpéjú Matori ṣá lọmọ́ wà tó ń gbé pawó ajé
Á máa jú ẹ ẹ́ ṣe Àmín àṣẹ
Bàbá Gbọ́njúbọ́lá mi bàbá Tòkunbọ̀ mi
Àyìnlá baba Dérìnsọ́lá
Ìrọ̀rùnọlá baba Quam mi o
Ọ̀rẹ ti Ìkẹ́olúwa Taofeek Àyìnlá
Àyìnlá mi small body
Big engine mo kí ẹ kí ẹ
Káre anobi gbogbo wa dede
Yusuf ọmọ’re ni
(Anobi gbogbo Mushin)
Yusuf ọmọ’re ni
(Anobi gbogbo Mushin)
Ẹlẹ́yinjú àánú
(Anobi gbogbo Mushin)
Àyìnlá Ẹlẹ́yinjú àánú
(Anobi gbogbo Mushin)
Èèyàn ti Ìkẹ́ Ànọ́bì
(Anobi gbogbo Mushin)
Yusuf ti gbogbo wa ni
(Anobi gbogbo Mushin)
Yusuf ti gbogbo wa ni
(Anobi gbogbo Mushin)
Gbogbo ẹ̀yin ọmọ Mushin
Ibi yòówù kẹ́ ẹ le wà
(Ẹ̀ ẹ́ kó èrè oko délé)
Ṣílé Kuranga Wálé Ìjàwáyé
Ẹ máa gbọ́ o pẹ̀lú Tọ́pẹ́
Gbogbo ọmọ Mushin lápapọ̀
Ibi yòówù kẹ́ ẹ le wà
(K’ẹ kó èrè oko délé)
Written by: Wasiu Ayinde Adewale Olasunkanmi Omogbolahan Anifowoshe

