Credits
PERFORMING ARTISTS
Sola Allyson
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Sola Allyson
Composer
Adewole Adesanya
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Sola Allyson
Producer
Sola Allyson Obaniyi
Producer
Lyrics
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi o
Nigbati eniyan ko mi le Iwo l'O gbe mi ro
Olutoju mi, Oluranlowo mi, Olugbamila
Enit'O s'aanu mi o
Modupe, Jehovah modupe
Modupe, Jehovah modupe
Fun imole t'Óo tan s'aye mi, O se o
Fun imole t'Óo tan s'aye mi, O se o
Modupe, Jehovah modupe
Modupe, Jehovah modupe
Fun imole t'Óo tan s'aye mi, O se o
Fun imole t'Óo tan s'aye mi, O se o
Jehovah l'O ba mi se
Eledumare l'O ba mi se
Atofarati l'O ba mi se
O ti tan 'mole s'ona mi, mi o ni si'na o
<span begin="3:09.504" end="3:15.116">Oun l'O gba mi, o gba mi o so mi d'afomo</span> <span ttm:role="x-bg"><span begin="3:11.231" end="3:13.825">(O gba mi)</span></span>
O tun tan imole s'ona mi, mi o ni si'na o
Modupe, Jehovah modupe
Modupe, Jehovah modupe
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye o
Iranwo yoo maa wa
Imuse yoo maa de
Agbara yoo maa so
Ohun mi a kari aye o
Ni iro ohun mi, gbogbo ese a sare wa
Lati wa ba o, iwo nikan lo ye mi ba
Ni iro ohun mi gbogbo okan a sipaya, lati ni irapada si igbala re
Ni iro ohun mi eti a te beleje, lati gbo ohun re iyen nikan l'o ye n gbigbo
Ni iro ohun mi oju á la sile kedere
Lati ri o, eni naa t'o ye n riri
Ni iro ohun mi, gbogbo ese a sare wa
Lati wa ba o, iwo nikan lo ye mi ba
Ni iro ohun mi gbogbo okan a sipaya, lati ni irapada si igbala re
Ni iro ohun mi eti a te beleje, lati gbo ohun re iyen nikan l'o ye n gbigbo
Ni iro ohun mi oju á la sile kedere
Lati ri o, eni naa t'o ye n riri
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye o
Iranwo yoo maa wa
Imuse yoo maa de
Agbara yoo maa so
Ohun mi a kari aye o
Written by: Adewole Adesanya, Sola Allyson