Lyrics
[Intro]
Nini
Nini de o
[Verse 1]
I called your phone but someone else picked up
Mafunmu rẹ o ta sansan
Ki la sọ, ki ni Laitan sọ?
Laipẹ, laijinna
Everything will fall into place
[PreChorus]
We can build a sky scraper
I won't be too ambitious
I won't think of building my home
Or we can build bridges
[Chorus]
Mo ni ko rọra gbe
O heavy, ma jẹ ko jabọ
Mo ni rọra gbe
O heavy
Rọra gbe, o heavy
[Verse 2]
Jabọ si ilẹ
Ma jẹ ko jabọ si ilẹ
Jabọ si ilẹ
[Verse 3]
I called your phone but you
Weren't there to pickup
Ara mi wa lọna
Otutu yii pọ
[Verse 4]
Don't leave me out in the rain
My frail heart can't stand the pain
O le so si mi lẹnu
Ko wa bu iyọ si
[PreChorus]
We can build a sky scraper
I won't be too ambitious
I won't think of building my home
And we can build bridges
[Chorus]
Mo ni ko rọra gbe
O heavy, ma jẹ ko jabọ
Mo ni rọra gbe
O heavy
Rọra gbe, o heavy
[Verse 5]
Jabọ si ilẹ
Ma jẹ ko jabọ si ilẹ
Jabọ si ilẹ
Jabọ si ilẹ
Ma jeko jabọ si ilẹ
Jabọ si ilẹ
[Refrain]
Mo ni
Just to know
Just to know
Just to know
Written by: Niniola Apata


