音乐视频
音乐视频
制作
出演艺人
Ajebutter22
表演者
STUDIO MAGIC
表演者
作曲和作词
Akitoye Balogun
作曲
制作和工程
STUDIO MAGIC
制作人
Platinum Toxx
混音工程师
歌词
Oya, oya, oya, oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Ká lọ ṣe wó
Naira show ati bai kini designer
T'ẹbá jókó, ẹ ti jẹ'gbín
Bi ìgbàtí everybody wọ áṣọ ẹbí
Mo ti rí iyawo, o dẹ fine nà
Ọmọ eko tó l'ọgbọ́n
Ẹ jẹ ká s'ounje, ka dá'nà
Á má dí titi yẹn, wọn tí dáràn
See mo handsome
You can ask her
Èmi graduate, mo ti gbá master
See I want to marry your daughter
Ẹ jọ sir, ẹ fún mi ni answer, ah
Yes ke
Ẹ sún sẹgbẹ
Oya lọ dress ke
Mo fẹ kọjá
Ẹ jọ ke gb'ẹsẹ̀
Má dẹ fíyin lẹ lẹsẹ̀ k'ẹsẹ̀
Ẹ jẹ a ko-ko-ko-ko, komọlẹ
Ẹ jẹ á jó-jó-jó-jó, jó dé'lẹ̀
Oya ko-ko-ko-ko, komọlẹ
Ẹ jẹ á jó-jó-jó-jó, jó dé'lẹ̀
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Ọmọ dára
Ọmọ tó dùn
L'ati Isale eko ati Ikorodu
Ítẹlẹ wà
Íbẹ lẹ wà
T'ó ba tẹ mi lọrún, má dẹ wá
Ni mo'n jo, mo'n jó, mo'n jó, mo'n jó, mo'n jó, mo'n jó bi werey
Ki n ṣe nítorí yin ni mummy wa lọ wé gele
Ah, gele skentele
Ah, gele skontolo
Ah, gele skentele
Ah, gele skontolo
Go down to your knees
Go down to your knees
Bi pé ẹ fẹ b'ẹ̀bẹ̀
Ijó ti dé, ijó ti dé, àwa nà ṣe fè bẹrẹ
Ẹ jẹ a ko-ko-ko-ko, komọlẹ
Ẹ jẹ á jó-jó-jó-jó, jó dé'lẹ̀
Oya ko-ko-ko-ko, komọlẹ
Oya jó-jó-jó-jó, jó dé'lẹ̀
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
Oya dìde
Jó nà
Ẹ wá jó bi bàtà yin n jó nà
Ẹ lọ si wájú
O ya padà
Mummy wé gele, daddy agbada
It's a dancing competition
Fine, fine bobo
Fine, fine baby
Dancing bobo
Dancing baby, oh
È jọ daddy
Idọbàlẹ mo wa
Mo fẹ b'ọmọ yin lọ
À le kọ́lé fún yin
À dẹ rá ṣọ fún yin
Á má travel lọ Dubai
Á má travel lọ Panama
È jọ daddy
Idọbàlẹ mo wa
Mo fẹ b'ọmọ yin lọ
À le kọ́lé fún yin
À dẹ rá ṣọ fún yin
Á má travel lọ Dubai
Á má travel lọ Panama
O ni gongo, o kárè
Ajebutter, Studio Magic
Ajebutter, Studio Magic
Ajebutter, Studio Magic
Ajebutter, Studio Magic
Written by: Akitoye Balogun


