歌词

[Chorus]
Insha Allah
Masha Allah
Ninu Mercedes
Ọta pọ gan-an awọn frenemies
Alaga ijoko bi Reminisce
Ibagaza mafia certified
Wo Spotify ti mo verified
Otamendi mafia multiply
Awọn Peter Rufai wọn o dẹ qualify
[Verse 1]
Insha Allah
Masha Allah
Million dollar ninu BTC
Wọn ni pe ẹ tun rale ni VGC
O de pada lowo lojiji
EDD EDD EDD
Aboki tẹwo mi GTB
Wọn lo local ko gba BET
Aro ba n gbọja mi CBD
[Chorus]
Insha Allah
Masha Allah
Ninu Mercedes
Ọta pọ gan-an awọn frenemies
Alaga ijoko bi Reminisce
Ibagaza mafia certified
Wo Spotify ti mo verified
Otamendi mafia multiply
Awọn Peter Rufai wọn o dẹ qualify
Written by: Jimoh idowu wasiu
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...