音乐视频

音乐视频

制作

出演艺人
Ayo Maff
Ayo Maff
声乐
Juju the Pen
Juju the Pen
伴唱
作曲和作词
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
AYORINDE AYODELE MAFOLUKU
词曲作者
Juju the Pen
Juju the Pen
词曲作者
制作和工程
Spaceboy Mercury
Spaceboy Mercury
制作人
oresanya michael
oresanya michael
录音工程师
Cheqwas
Cheqwas
混音工程师

歌词

[Verse 1]
Fifteen years old mo sa n'le
Owo ni mo ti
Owo ni motivation
Mumsy
I no fit dey watch you dey suffer
So, mo ṣe dating
Ah, mo ṣe local
Ṣebi
I no know say music go go far
The day wey you go meet your helper, your story go change
Ayo Maff, ọmọ owo mi ṣo damọ to ba ri?
E no easy, mo tira mi mọle fun ọjọ mẹjọ
E no easy, mo tira mi mọle fun ọjọ mẹjọ
[PreChorus]
Ah iku to pa iya teacher to le pa awọn n**a
F'awọn n**a mi silẹ
I pray we get bigger
Ah iku to pa iya teacher to le pa awọn n**a
F'awọn n**a mi silẹ
I pray we get bigger
[Chorus]
Ah, kaye ma sọ wa sokunkun alẹ
Ah, kaye ma sọ wa sokunkun owo
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
[Verse 2]
Mo woju Oluwa
Mo woju Oluwa
Mo gbadura mo pray for mercy k'emi ma lọ jabọ
Ko sẹni ti mo gbojule ọwọ rẹ mo wa
Iwọ ṣa lọlọkọ mi, wa mi sibi to da
Obinna, oore to ṣe fun mi lọjọsi
Ẹ wo aye mi lode orin mi l'ọn jo si
Elijah, Elijah holy Micheal wa loda
Ayo Maff ẹyọ kan ni you no fit see another
[PreChorus]
Ah iku to pa iya teacher to le pa awọn n**a
F'awọn n**a mi silẹ
I pray we get bigger
Ah iku to pa iya teacher to le pa awọn n**a
F'awọn n**a mi silẹ
I pray we get bigger
[Chorus]
Ah, kaye ma sọ wa sokunkun alẹ
Ah, kaye ma sọ wa sokunkun owo
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
Mo gberin ojo latoke emi ni kan
Written by: AYORINDE AYODELE MAFOLUKU, Juju the Pen
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...