歌词

Uuuhh, sebe le ma sun? (Sebe le ma-?) Ojo re bi ana ta gbominira, 1960 Nigba yen, things easy Gege bo se wi Ta rugbo, tomidan L'o n dunu, pa tin gbominira Omi inira, indeed abi ewo naira wa Ilu polukulumushu Tewe, tagba lon jeyan won nisu Abe ori? Ewe eri, sugbo e ofewi Abe ori? Agba eri, atenuje lofe pa yin Pete-pete tana ni popa Eni bataba kolo mofe ni Sebe lema sun? Teba sope omo nkan-kan Eyin aro lema waa (sebe la maa) Mewa nsele o Sebe lema sun? (Sebe lema sun un?) Eni woseju akan o Eyin aro lema waa Mewa nsele o Kini suuru tio lere? Kini ise, ti ko sere? Won sa leyan tio loruko Okuku sise oden rere e Aah, ede sope a siwa l'omode Nkan sa l'eiye nje kagbado tode 9ice, oro gidi loso Oro to o nilari loso Anlati fi laka yesi Kasoro sibi torowa Sebe le masun oo? (Sebe le masun un?) Eyin aro lema wa a (sebe lema sun un?) Mewa nsele o Sebe lema sun un? Teba ro seju akan Eyin aro lema wa o Mewa nsele o Odi asiko ibo yen Won wa s'adugbo Won asomo je-je Eje kan wole tan Gbogbo eje tan je (kai!), la wo kese Toba tun se were la siko ibo Won ani kodo tolo bere Won a senu mere Kalo-kalo gbe nkan mi senu uye (kalo-kalo senu uye) Afira aditu ti iwole Talo dibo fun un? Pasan ta fi na yale Onbe lori aja fun un un Odo elo tunramu Ema jo anpagbon ni funfun Fun yin Mowi temi ii— Asegbe kan kosi oo Asepamo lowa (beni, beni, beni, beni—) Ase sile labo waba Emi oti iku, mo sile sise Mo sile fowo wewo Mo sile tule mise iiiii Sebe lema sun un? Teba sope omo nkankan Eyin aro lema wa a Mewa nsele o Sebe le ma sun un? Eni woseju akan o Eyin aro lema waa Sebe le maa? (Mewa nsele o) Lema sun un Asa o se, omo nla Lema sun un Lema sun un Lema sun un Sun un
Writer(s): Lara George Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out