album cover
Ayedun
26,281
世界音樂
Ayedun 由 YBBM 於 2020年11月26日發行,收錄於專輯《 》中Alagbe
album cover
專輯Alagbe
發行日期2020年11月26日
標籤YBBM
旋律
原聲音質
Valence
節奏感
輕快
BPM100

音樂影片

音樂影片

積分

歌詞

Seribumi
Seribumi elédè kewu (Shocker lo ṣe beats)
Iji ra
Qdot lórúkọ tèmi
Qdot lórúko mí oohh, eh-oh
Àyé là bowó (ayé là bowó)
Àyé là má fí silẹ lọ (silẹ lọ)
Ayànmọ pẹlú kádàrá wọn yàtọ sírà wọn
Òní k'ajá má gbé nílé, ó yàn kinihun sínú igbó
T'óbá lówó ló d'àwo ilé àyé (yeah oh, e eh-eh)
O lówó lọwọ, ó d'ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé?)
Olówó l'ayé má fún láyè, torí olówó l'ayé fẹ rí
Ẹlẹdàá mí o ṣemí lẹni àyé fẹ rí (Ẹlẹdà mí, oh-ohh)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ero mí tó ń jò, tó ń jo lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ'run lóbá mí ṣe (yay)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ'run lóbá mí ṣe
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ọrẹ, wo, owó lafi ń ṣe ilé àyé
Ìwà ló má fi ń ṣe ọrùn (fi ń ṣe ọrun)
Bóṣé lówó tó o, lomá gbádùn òyìnbó to
Lomú Davido ọmọ Bàbá Olówó pariwo p'owó ní kókó
Money good ohh, ohh
Poverty no sweet oh, my brother
T'óbá lówó lo d'àwo ilé àyé (ooh, ooh, yeah-yeah-yeah)
Ó lówó lọwọ ó d'ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé o?)
Olówó láyé má fún láyè, torí olówó láyé fẹ rí
Ẹlẹdàá mí oh, ṣemí lẹni àyé fẹ rí
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi (ayy-ayy, oh)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe (bá mí ṣe)
Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi
Àyé dùn (àyé dùn jẹ jù'yà lọ)
Àyé yí dùn (àyé dùn jẹ jù'yà lọ)
Orí ṣe mí l'olówó àyé (àyé dùn jẹ jù'yà lọ)
Bí tí Wasiu Ayinde o (àyé dùn jẹ jù'yà lọ)
Bí tí K1 De Ultimate (àyé dùn jẹ jù'yà lọ)
Shout out to Mayegun gbogbo ilé Yorùbá
Yeah, who's here?
Written by: Fakoya Oluwadamilare, Mudashiru Olajide
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...