歌詞

The next song is called Olánrewájú Why you think say I wear native come? Igba o lọ bi orere Bo ba koro oṣi maa dun ah Eni to ni suuru kii ṣeyan kekere Bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e, ẹh a ẹh Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ, ẹh a ẹh Olánrewájú ọmọ ọba E ma suure da gba Won ni ko o ṣe were, roora ṣe E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku si bi ọtẹ oo Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure da gba oo E ma suure da gba Igba o lọ bi orere B'ọmọde oku o, oṣi maa da gba Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu ah Gbogbo eni abi lo ma ku eh, ẹh a ẹh Iwa ta a wu lo ma ku ah, ẹh a ẹh Olánrewájú ọmọ oba, e ma suure da gba o Won ni ko ṣe were, roora ṣe E ma suure da gba o Olooto ko ni ku sibi ọtẹ o Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure da gba o Olooto ko ni ku sipo ika o Olooto ko ni ku sibi ote o Olánrewájú ọmọ ọba, e ma suure dagba o Olánrewájú ọmọ mi, e ma suure dagba o
Writer(s): Olawale Ibrahim Ashimi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out