Lyrics

Odin-din ọmọ (odin-din ọmọ) Uh-uh-uh Wicked (allow) Wo, so many things wey don sup (sup), iron wey don rust (allow) People wey don kpeme, body wey don rot Jẹjẹ ní mọ ṣáyé, miofe báwọn k'aba mọ (wo, wo, wo) Mode bẹ'rù àyé tótó, ọmọ ẹ'dá adamọ See, I dey work, I dey pray, all my giants I dey slay (slay) Tàn imole sáyé mí, I don't wanna go astray Make my hustle pay (pay), k'ogun àyémi fail (fail) K'ìjì ma jamí, kí ńmá ṣe r'ogun hurricane (allow) Bàbá l'òkè, jọ'wọ', ṣ'Ami s'àdúrà mí (s'àdúrà mí) Funmi ní Ferrari, k'owá bámi m'Acura mí (m'Acura mí) Funmi lágbára, májẹ kó remi (allow) Ma jẹk'àiyé yemi, má jẹk'ojú timí (wo, wo, wo) Uh, e don dey tay wey I don dey ask You (ask you) For the money, kinle ball bi Lukaku (bi Lukaku) Uh, and I know say You go run am (allow) 'Cause for me to be broke is a taboo Me, I no pray make person own spoil oh Say my own e no fit spoil oh Make my metal no rust, make dem no find me oh Ki mummy mi jèrè mí oh Daddy ti ṣ'àdúrà fún mí oh Wípé mámálo, mámábo oh Ńkan òní tabala mí lésẹ, oh na, bala mí lésẹ oh Ṣebi you talk say I no go beg for food Òun t'ẹnu májẹ, o tí dá látìgbà t'oti dàmi Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way, no way, no way Ma fimisilẹ Bàbá, no way, no way Bámi ṣ'Ami ṣ'àdúrà mí, bí mọ ṣe ń hustle (bí mọ ṣe ń hustle) F'ìdáhùn sí ìbe'rẹ' mí, bí mọ ṣe ń rọju (ṣe ń rọju) Jẹ'kí irawo mí tàn, k'ọmọ yìn bubble (allow) Adùn niko gbẹ̀yìn ẹ, bí mo ṣe ń struggle (Jésù) 'Cause, 'cause nkan yapa t'ojú ri Motí kò iyepe filling, mo déti ṣ'alàgbàfo rí (ṣ'alàgbàfo rí) Uh, modupẹ torí Ìwọ l'alàgbàwí (allow, allow) You're the reason for my riches, Ìwọ l'oṣe rábà yii Ọmọ gutter di onílé, d'onílé odi olọ'nà (di olọ'nà) Owó ní mo wa, mò pàdé ọla, àti iyì l'ọ'nà Eyán Tope Alabi, ore mí o common Mu lamba sílè kàn mo, gbọ l'àiyé dé Aljana (wo, wo, wo) God, I wanna thank You for Your blessings (for Your blessings) For the ups and downs, for the lessons (for the lessons) Ogun àyémi létí ṣẹ ńsìn (otí ṣẹ ńsìn) Ẹni p'orímí níbí o má tẹsi Me, I no pray make person own spoil oh Say my own e no fit spoil oh Make my metal no rust, make dem no find me oh Kí mummy mí jèrè mí oh Daddy ti ṣ'àdúrà fún mí oh Wípé mámálo, mámábo oh Ńkan òní tabala mí lésẹ, oh na, bala mí lésẹ oh Shebi you talk say I no go beg for food Òun t'enu májẹ, o tí dá látìgbà t'oti dàmi Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way, no way, no way Má fimisilẹ Bàbá, no way, no way Wozzy (wozzy) Wicked (Spyritmyx)
Writer(s): Superwozzy Superwozzy Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out