Lyrics

Gbogbo owó tí mo na (oya, oya, move) Fún ọjọ' méje (ko, kober!) Gbogbo owó tí mo na Kò gbe ogungunnisọ fún mí Èmi ọmọ oró, I no fit pass my lane Wọn ni kin ma jáde, but wọn lé mi Èmi ọmọ owó, I no do pass myself Wọn ni kín má sáré, but wọn le mi-i So, I can not see my brother Ojo (Ojo o...) And popo them don lock my brother up o Say, make them free my brothers, oh-oh Them no kill person, them be ọmọ owó, oh Ajé ogugulusọ o (ah, o kúkú ni sọ fún mi) Ah, o kúkú ni sọ fún mi (ah, o kúkú ni sọ fún mi) Ah, o kúkú ni sọ fún mi (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi) Mo mọ pe o kúkú ni sọ fún mi Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi Ki ọta mi le ri ran wo Ki ọta mi le ri ran wo Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa Ki ọta wá le ri ran wo Ki ọta wá le ri ran wo Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi Ki ọta mi le ri ran wo (mo mọ pe kúkú ni sọ fún mi) Ki ọta mi le ri ran wo Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa Ki ọta wá le ri ran wo Ki ọta wá le ri ran wo I've been thinking, I've been too deep in my feelings Bless my pocket, ṣé mi l'ọmọ t'ọ ma jí ri If I no hustle who go take care of my siblings If I no hustle who go take care of my siblings Mo sare wọ Jerusalem, mo gbàdúrà ki n le pa'wo If ọlọ́pàá no lock Ojo up, my brother he dey yawo Man make man kàlà Ẹjẹ lo jú mi Man make man kala, ah Ẹjẹ lo jú mi Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje Mo w'ọṣẹ dúdú, kọ ọjọ to lọ-ọ Gbogbo owó ti mo ná fún ọjọ méje Mo w'ọṣẹ dúdú, ọjọ le lọ Ah, ki ikú ma pa aláàánú mi Ki ọta mi le ri ran wo Ki ọta mi le ri ran wo Ah, ki ikú ma pa aláàánú wa Ki ọta wa le ri ran wo Ki ọta wa le ri ran wo (koba!)
Writer(s): Abatan Eniolaoluwa Olumide, Adisa Oluwatomi King, Ayomide Mafoluku Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out