Στίχοι

Àlàyé mí bá mí sọrọ kàn, kí lo ń lọ? (Kí lo ń lọ) For my area, ọrọ mí lọ ń sọ (lọ ń sọ o) Wọn ní mo give them pressure, pressure Ò jẹ máà lọ sún, ṣíṣẹ lọ Ọmọ ìyá, pá'wó lọ Nobody go dey when sapa don too much Ẹnì to bà bá ṣ'òun ṣa lo mọ Kabo, kabo lọ, ọmọ'ba ṣìn lọ E still dey lit, but e still dey hot Happiness, ẹ rí finesse My life no stress, fine boy, no ex Happiness, ẹ rí finesse My life no stress O tútù, o tútù, o wọ 'yin o Má gara sí mí, alakọri o Òun to ń ṣe yìn kọ lo ń ṣe mí o Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe, I no be novice Yepa, yepo, àṣàmọdi o Ọga, no dey form over sabi o Michael Scofield, as you can see I be zombie, sir, kò kàn mi o O tútù, o tútù, o wọ 'yin o Má gara sí mí, alakọri o Òun to ń ṣe yìn kọ lo ń ṣe mí o Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe, I no be novice Yepa, yepo, àṣàmọdi o Ọga, no dey form over sabi o Michael Scofield, as you can see I be zombie, sir, kò kàn mi o Got your birthstone, you a earth tone I miss you, need you bad, baby, come home You want me, make it happen, baby, I know Want me to keep you happy, baby, I know Penthouse, and a condo Got no one, amapiano You want me, make it happen, baby, I know I'm here to make you smile when you feel low Happiness, ẹ ri finesse My life no stress, fine boy, no ex Happiness, it's a feeling Your life no stress O tútù, o tútù, o wọ 'yin o Má gara sí mí, alakọri o Òun to ń ṣe yìn kọ lo ń ṣe mí o Ẹ jẹ lọ mọ òun t'ẹ ń ṣe, I no be novice Yepa, yepo, àṣàmọdi o Ọga, no dey form over sabi o Michael Scofield, as you can see I be zombie, sir, kò kàn mi o
Writer(s): Osabuohien Osaretin, Sergio Kitchens, Ololade Ahmed, Dave Nunes Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out