Music Video

7 DAYS
Watch {trackName} music video by {artistName}

Credits

PERFORMING ARTISTS
Ayo Maff
Ayo Maff
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adisa Oluwatomi King
Adisa Oluwatomi King
Composer
Abatan Eniolaoluwa Olumide
Abatan Eniolaoluwa Olumide
Composer
Ayomide Mafoluku
Ayomide Mafoluku
Lyrics

Lyrics

Gbogbo owó tí mo na (Ayo-Ayo Maff) Fún ọjọ' méje (the vibe) Gbogbo owó tí mo na Ajé ò kúkú ní sọ fún mí Èmi ọmọ oró, I no fit pass my lane Wọn ni kin ma jáde but wọn lé mi Èmi ọmọ owó, I no do pass myself Wọn ni kín má sáré but wọn le mi-i So, I can not see my brother Ojo And popo them don lock my brother up o Say, make them free my brothers oh-oh Them no kill person, them be ọmọ owó oh Ajé oguguluso o (o kúkú ni sọ fún mi) Ha-a o kúkú ni sọ fún mi (o kúkú ni sọ fún mi) Ha-a o kúkú ni sọ fún mi (o kúkú ni sọ fún mi) Mo mọ pe o kúkú ni sọ fún mi Gbogbo owó ti mo ná, fún ọjọ méje Mo we ose dúdú, kọ ọjọ to lọ ọ Gbogbo owó ti mo ná, fún ọjọ méje Mo we ose dúdú, ọjọ le lọ Ah ki ikú ma pa alaanu mi Ki ọta mi le ri ran wo Ki ọta mi le ri ran wo Ah ki ikú ma pa alaanu wa Ki ọta wá le ri ran wo Ki ọta wá le ri ran wo Ah ki ikú ma pa alaanu mi Ki ọta mi le ri ran wo (aje o kúkú ni sọ fún mi) Ki ọta mi le ri ran wo Ah ki ikú ma pa alaanu wa Ki ọta wá le ri ran wo Ki ọta wá le ri ran wo I've been thinking I've been too deep in my feelings Bless my pocket, se mi l'ọmọ tán ma jí ri If I no hustle who go take care of my siblings If I no hustle who go take care of my siblings Mo sare wọ Jerusalem Mo gbàdúrà kin le pawo If ọlopa no lock Ojo up My brother he dey yawo Man make man kàlà Ẹjẹ lo jú mi Man make man kala ah Ẹjẹ lo jú mi Gbogbo owó ti mo ná, fún ọjọ méje Mo we ose dudu, kọ ọjọ to lọ ọ Gbogbo owó ti mo ná, fún ọjọ méje Mo we ose dúdú, ọjọ le lọ Ah, ki ikú ma pa alaanu mi Ki ọta mi le ri ran wo Ki ọta mi le ri ran wo Ah, ki ikú ma pa alaanu wa Ki ọta wa le ri ran wo Ki ọta wa le ri ran wo
Writer(s): Abatan Eniolaoluwa Olumide, Adisa Oluwatomi King, Ayomide Mafoluku Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out