Hudební video
Hudební video
Kredity
PERFORMING ARTISTS
Tkeyz
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Tkeyz
Songwriter
Oluwatosin Akinsuyi
Songwriter
Texty
[Verse 1]
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni o
Ologojulọ
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni o
Ologojulọ
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ, eh
Jesu Iwo loluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
[Chorus]
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni Ọ
Ologojulọ
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni o
Ologojulọ
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni o
Ologojulọ
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni o
Ologojulọ
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
[Chorus]
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
[Chorus]
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
[Verse 2]
Ikan lana
Ikan loni lo jẹ
He is the Ologojulọ
Iwọ lo mọ mi
Iwọ lo si mọ mi
Even before I was born He knew me
Omi eemi iye sinu mi
O sọ mi dalaye
You anointed me and You appointed me
Iwo lologojulọ
You never fail, You never disappoint me, no no no no
Just by a word He made the heavens and the earth, just by a word
Iwọ lologojulọ
[Chorus]
You are Jesu
Oluwa Orukọ o rẹ ga
Ologo
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
[Chorus]
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
[Bridge]
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga o
Ologo
Jesu Oluwa, e
Orukọ rẹ ga, e
Iwo lologojulọ
Jesu Ọba mi
Jesu Baba mi o
Jesu Iwọ lologo
You are the one who existed even before the beginning begun
Jesu
Jesu, Jesu, Jesu
Ologo
[Chorus]
Aiku, Aiṣa
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni Ọ
Ologojulọ
Aiku, Aiṣa
Ailedibajẹ ni Ọ
Iwọ lologo
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Iwọ lologojulọ
Jesu Oluwa
Orukọ rẹ ga
Ologojulọ
Jesu
Jesu, Jesu, Jesu
Jesu
Ologojulọ
Jesu
Jesu
Jesu
Ologojulọ
[Outro]
Jesu
Jesu, Jesu, Jesu
Jesu
Jesu, Jesu, Jesu
Ologojulọ
Written by: Oluwatosin Akinsuyi


