Kredity

PERFORMING ARTISTS
Teejay’s WRLD
Teejay’s WRLD
Performer
Tajudeen Umar Àdé
Tajudeen Umar Àdé
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Tajudeen Umar Àdé
Tajudeen Umar Àdé
Arranger
Adé Orí ọ̀kín
Arranger
PRODUCTION & ENGINEERING
Tajudeen Umar Àdé
Tajudeen Umar Àdé
Post Production Engineer
Adé Orí ọ̀kín
Recording Engineer

Texty

[Verse 1]
You get money, you dey form boss
Teejay's WRLD gan-an gan-an ni idan
Nitori ọmọge Island la ṣe n tanna
[Verse 2]
Ẹnu gbẹ nitori owo ti tan
Oluwa lo ṣeyi eeyan kọ
Na me be next, emi lo kan
[Verse 3]
I always dey loaded, koju ma lọ ti mi
Ti ba bun ẹ, ko ki n ṣe pe sara yọ si mi
O le jẹ Oluwa lo ran mi si ẹ
Lucky day na the day I always expect
[Verse 4]
Ọla Oluwa ṣa la n jẹ
Niwaju awọn temi emi o bajẹ
Wetin dey happen ki lo n ṣẹlẹ
Ṣa cana ko ba le fi wahala silẹ
[Chorus]
Asalamaleku kolo wa da?
Cana dey ko wa gba
Eh Casablanca
Ṣo ma n gba?
[Chorus]
Asalamaleku kolo wa da?
Cana dey ko wa gba
Ah Casablanca
Written by: Tajudeen Umar Àdé
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...