Kredity
PERFORMING ARTISTS
Ebenezer Obey
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Ebenezer Obey
Songwriter
Texty
Lai f'ota pe
temi adara
Lai f'ota pe
temi adara
Ota ile ota ode o, eje lo dake
Ona wo la le gba
T'a ofi T'aiye lorun ooo
Ona wo la le gba
T'a ofi T'aiye lorun ooo
T'o ba ndara fun e
awon ota binu, ahaa ko dara
T'o ba ndara fun e
awon ota binu, ahaa ko dara
Iwa aidara pelu inu ni bini
Ko le da nkankan
T'o ba ndara fun e
awon ota binu, ahaa ko dara
Iwa itaara pelu inu ni bini
Ko le da nkankan
Written by: Ebenezer Obey, Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi