Musikvideo

Musikvideo

Songtexte

Kere ooo, kere ooo
K′omo ile ko gbo ko sofun t'oko Oba to dari afefe
Oba to dari ojo na
Wa dari mi niii
Ko fasepe re han oo
Oba Alasepe
Saki ooo
Oba to dari afefe oooo Oba to dari ojo na
Wa dari mi iii
Ko fasepe re han oo Oba alasepe
Jiji moji lowuro oo Mo k′epe oooo Oba alesepe Oooooooo
Wa so ofo mi dogo ooo Ahhhh
Oba alesepe
 Oba Alasepe
Wa sekun mi derin ooo
Oba apebo
Oba apesin
Ona na ehhhhh, ona na oohhh Oba alasepe
Agan n bi were ooo
Afoju si riran gbola
Oba to laju afoju
Bi mo se nlo
Bi mo n se de
Baba agba oooo
Fiso reso mi oooo
Iwo ooo s'aseti ri baba oo
Oba alasepe
Oba alasepe
Edua to n dari aye si isale o Ase oke oku ojo pipe
To file orun soke
Mo gba ye mi de oo
Wa dari mi sayo
 Ki nsogo alade mimo To dari mi nu ojo Olowo sisan ara
Oba lailai
Mo gboju mi soke si o olu nla
Afo hun ko se wa
Ase ti ngboro soke
Dari mi oooo
Oludari awon okun
Ibi to ba to wu efufu lele ni dari igbesi oo Ibi to ba wu olowo eni ni rani lo
Ah ah ah oba alesepe ee
Oba to dari afefe Ahhhh
Olu nla to dari ese mi Wa darimi
Ko fasepe re han ooo Oba alasepe
Baba nla ase ori aye Emi inu awon woli Oba to dari afefe oo
 Eda alailesi Saaki Toberu Toyin
Eda ti nbe lai beru ki nbeyan ooo Wa dari mi
Ah ah ah ah ah ah........ah ah ah Oba alesepe
Written by: Paul Tomisin
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...