album cover
Armstrong
10
Music
Armstrong wurde am 20. Januar 2025 von Fuji Repete/K1 De Ultimate Media als Teil des Albums Appreciation veröffentlicht
album cover
Veröffentlichungsdatum20. Januar 2025
LabelFuji Repete/K1 De Ultimate Media
Melodizität
Akustizität
Valence
Tanzbarkeit
Energie
BPM124

Credits

PERFORMING ARTISTS
K1 De Ultimate
K1 De Ultimate
Performer
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Drums, Keyboards
COMPOSITION & LYRICS
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Olasunkanmi Ayinde Marshal
Songwriter

Songtexte

Aláyélúwà àṣẹ á pẹ́ lẹ́nu baàmi
Ọba Ẹ̀lúkú lukumonu Ẹ́bìdènà Toki omo Fákọ̀yà
Ìwọ lo ga jù lábà láàrin wa Ọmọ́gbọ́láhàn òun ni
Torí bó ti ń tẹ̀ Toki Toki ló ga jù
Àpésìnọlà mi kiní man ò ní ṣe ẹ́ kò ko ko lara ọta ń le
Wàá máa wà nínú ọlá ńlá
Èèyàn tèmi Àyìndé mi Wasiu a ti jọ mí ṣeré bọ̀ tipẹ́tipẹ́
Àpésìn ikú òní pa ẹ́ fún mi Àmín o
Gbogbo yín ẹ kú àdúrótì
Armstrong ó ní n bá’un kí gbogbo yín
Ó ní ẹ ṣeun ṣeun
Ọmọ dáadáa ni Armstrong ọmọ àwọn àgbà ni o ó dẹ̀ mọwọ́ wẹ̀ Tèmítọ́pẹ́ B’ọ́mọdé bá mọwọ́ wẹ̀ Àyìndé Ọmọ́gbọ́láhàn á máa bá àwọn àgbà jẹun
Ẹ́bìdènà ọmọ gidi ni
Tèmítọ́pẹ́ Armstrong o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn
Wàá máa lékún nínú ọlá nínú àlàáfíà wàá máa lékún
Kábíèsí Ọba Ṣẹ́gun alówóńlé
Síbẹ̀síbẹ̀ Olúwa ń bẹ pẹ̀lú mi kiní kan ò ní ṣe mí
Ṣẹ́gun àṣẹ á pẹ́ lẹ́nu kánrin kése o Ọba Adéṣẹ́gun
Armstrong Chairman mi Aerofield home and properties
Èèyàn Fẹ́mi ọmọ Adélẹ́yẹ ó Captain
Tèmítọ́pẹ́ Akíntúndé ọmọ Governor Dàpọ̀ Abíọ́dún
Kó o bá mi kí Governor, kó o bá mi ki dáadáa
Dàpọ̀ Abíọ̀dún ọmọ Ọba pàtàkì awo tèmi Àyìndé mi Wasiu
Kó o bá mi ki bo bá délé
Armstrong o ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn owó ọmọ á bá ẹ gbé
Camera tèmi nìyẹn K1 De Ultimate ẹ má ṣe bínú
Armstrong mi (Armstrong mi)
Tèmítọ́pẹ́ mo kí ẹ (Armstrong mi)
Tèmítọ́pẹ́ mo kí ẹ o (Armstrong mi)
Ọmọ Akíntúndé mi Armstrong (Armstrong mi)
Ilé kíkọ́ lọmọ ń tà (Armstrong mi)
Ilé kíkọ́ lọ́wọ́ ẹ ló wà (Armstrong mi)
Òun ni president
Tempo!
Tèmítọ́pẹ́ mi Armstrong (Armstrong mi)
Ọmọ Dàpọ̀ Abíọ̀dún mi Armstrong (Armstrong mi)
Ọmọ Dàpọ̀ Abíọ̀dún ni Armstrong (Armstrong mi)
Ilé kíkọ́ lọmọ ń tà (Armstrong mi)
Tèmítọ́pẹ́ mi Armstrong (Armstrong mi)
Ọmọ Akíntúndé yí ọ́ da fún ọ tí ọ́ pọ̀ ( Armstrong mi)
Àsùngbàgbé ò ní kàn ẹ́ (Armstrong mi)
Ilé kíkọ́ lọmọ ń tà (Armstrong mi)
Èèyàn olórí ẹgbẹ́ wa o (Armstrong mi)
Èèyàn olórí ẹgbẹ́ wa (Armstrong mi)
Èèyàn t0’olórí ẹgbẹ́ wa (Armstrong mi)
Ọmọ́kẹ́hìndé, Asobe Asobe
Èèyàn kẹ́hìndé Asọ́bẹ (Armstrong mi)
Èèyàn kẹ́hìndé Asọ́bẹ (Armstrong mi)
Èèyàn Tinubu l’Asọ́bẹ ( awo Armstrong mi)
Èèyàn Tinubu l’Asọ́bẹ ( awo Armstrong mi)
Armstrong, yí ó da fún ọ tí ọ́ pọ̀ (Armstrong mi)
Kó o tọ́jú first vice Ọpẹ́olúwa Awónúbi
Kó o tọ́jú second vice, Dayọ̀ James Akéréle
Kó o tọ́jú Secretary Gafar Adéṣọ̀gá
Kó o tọ́jú assistant secretary Bọ́lá Ahmed ọmọ Awótúbọ̀
Kó o tọ́jú Treasurer Títílayọ̀ Ọshin
Kó o tọ́jú Financial Secretary Bánkọ́lé Kazeem Ògúnnọ̀wọ̀
Kó o tọ́jú Publicity Secretary Babátúndé Adéléyè
Tọ́jú Chief Whip Wasiu Mustapha
K9 o tọ́jú Editor Nurudeen Àbáyọ̀mí ọmọ Ọdúntàn
Ex official 1 Rt Honourable Adétúnjí ọmọ Òrìṣàladé
Kó o tọ́jú ẹ̀ official 2 prince Gbolahan Ọ̀shọ́
Kó o tọ́jú social secretary Olúbùnmi Adétọ́lá Allen
Olórí ẹgbẹ́ ni Armstrong (Armstrong mi )
Christ Apostolic Grammar School Old Students Association
Mo kí ẹ Armstrong (Armstrong mi)
Mo kí ẹ Armstrong (Armstrong mi)
Olórí ẹgbẹ́ (olórí ẹgbẹ́)
Olórí ẹgbẹ́ (olórí ẹgbẹ́)
Old Students Association (olórí ẹgbẹ́)
Old Students Association (olórí ẹgbẹ́)
Number 1 mi (Number 1 mi)
O ò dẹ̀ ní dọlárẹ̀yìn o (Number 1 mi)
Ọmọ Dàpọ̀ Abíọ́dún ni Armstrong (Armstrong mi)
Ọmọ Dàpọ̀ Abíọ́dún ni Armstrong (Armstrong mi)
Bó o bá délé bá mi kí Governor
Ọmọ ọmọ Dàpọ̀ Abíọ́dún
Ní mo ní ó máa bá mi ki dáadáa
Èèyàn t’Adégoróyè (Adé orí ọ̀kín)
Èèyàn K1 De Ultimate (Olórí ọmọ Ọba níjẹ̀bú)
Èèyàn t’Àyìndé Wasiu (Olórí ọmọba níjẹ̀bú)
Bíbíire ò dẹ̀ ṣe é fowórà (Adé orí ọ̀kín)
Bíbíire ò dẹ̀ ṣe é fowórà (Adé orí ọ̀kín)
Yèyé Oòduà Oseni Toyin Òkìkí
Awo abosia tí ò common
Armstrong mi (Armstrong mi)
Armstrong mi (Armstrong mi)
Yèyé Oòduà Armstrong ní n kí ẹ (Armstrong mi)
Oṣé o Armstrong mi (Armstrong mi)
Apẹ́lógun ká relé
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Apẹ́lógun ká relé ò
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Apẹ́lógun ká relé ò
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Bàbá Adini ká relé o
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Ọmọ Apẹ́lógun ká relé
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Apẹ́lógun ká relé ò
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Apẹ́lógun ká relé
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Ọmọ Apẹ́lógun ká relé o
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Ah! Bàbá Adini ká relé o
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Shamsudeen Adébáyọ̀ ká relé o
(Orí oyè í sùn’de o eh)
Apẹ́lógun ká relé
(Orí oyè í sùn’de o eh)
All rounder ire ni
Bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (all rounder ire ni)
Apẹ́lógun Samsudeen (all rounder ire ni)
Bí ìwọ bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (all rounder ire ni)
Bàbá Adini gbogbo t’Ògùn State
Bí o bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (all rounder ire ni)
Bo bá ti ń lọ bí o bá ń bọ̀ (all rounder ire ni)
Shamsudeen (all rounder ire ni)
Adébáyọ̀ (Adébáyọ̀ ire ni)
Bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (Adébáyọ̀ ire ni)
Bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ o (Adébáyọ̀ ire ni)
Armstrong ní n kí ẹ o (Adébáyọ̀ ire ni)
Bàbá Adini, àgbà musulumi gbogbo t’ògùn State
Ẹ̀sìn gangan ọwọ́ ẹ ló wà (Adébáyọ̀ ire ni)
Bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (Adébáyọ̀ ire ni)
Bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (Adébáyọ̀ ire ni)
Bàbá Adini (Adébáyọ̀ ire ni)
All rounder bó bá ń lọ bí o bá ń bọ̀ (Adébáyọ̀ ire ni)
Owó ẹgbẹ́ ni ẹ dapadà
Owó ẹgbẹ́ ni o
Má fi s’ápò o
Ẹ mu fún Benjy
Ẹ̀ ń bẹ́
Ògìrì o ò farabalẹ̀
O ò farabalẹ̀ ò ń bẹ́
Okay Casamingo o ò farabalẹ̀
O ò farabalẹ̀ ò ń bẹ́
Written by: Olasunkanmi Ayinde Marshal
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...