album cover
Mandem
4.692
Afro-Beat
Mandem wurde am 1. August 2025 von Scolly Entertainment als Teil des Albums veröffentlichtMandem - Single
album cover
Veröffentlichungsdatum1. August 2025
LabelScolly Entertainment
Melodizität
Akustizität
Valence
Tanzbarkeit
Energie
BPM115

Credits

PERFORMING ARTISTS
Islambo
Islambo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Samuel Ashaye
Samuel Ashaye
Songwriter

Songtexte

Hold something
Bobo alashakasha
Aiyayayaya
Bobo alashakasha
O sunu lapa b
O sunu lapa c
Observation no be felony
Má ṣe ogun sí ọ̀gá e, fi owó jẹ Indomie
Ngbo, them say street no get memory
Ọgá ò, a fe to ten story
Everybody know it’s a vibe
Gbajúgbajà ìlú mo ká yìí
Ó ń gbé wọn lọ free ride
Ó ń sonu this side
Bóbo kò ń pẹ̀dé ọmọ mi pro
Ẹ ma wo Ìjọ L’ẹsẹ́ negro
Tó ń gbó vibe, kò ṣe ní jó
Ti àwọn Arábọ̀ gan ò ṣe kó
Oya, wọ́n ti sọ d’anthem
Owa dì orín àwọn mandem
Ayé ò le, ọmọ Ọba kí ẹ
Ìwọ ló ní owó inú bank ẹ
Hold something
Osu lapa bi
Ká rí nkan jẹ, ká rí nkan chop
I’m displaying my own caricature
In a comical way Ẹ̀jẹ̀ kọ́ ọmọ yín káwé
 
Mo wọ́ club, Italo mo gbé
Ìyẹ̀ ara, ara kéngẹ
Make my body no calm
Ọmọ tún ni yo fam
Eni ni ìgbàgbó, pé ọjà ilé yàtọ̀
Ó kọ́ kan mí ní ìpàkò
What you saying, i’m going fam
Ìgbà n bájọ, lónìí ìlù gbé ìlù
(gbelu)
Ìṣé owó Mr. Peteru
Apa, lo n je the boy is very good
sha Làtẹ́wọ́ bí ti cheribum
Gbesòrí lati lungu de oniru
Bí alfá tó mọ̀ kẹ́wú jù
London lagos
Oya, wọ́n ti sọ d’anthem
(Anthem)
Owa dì orín àwọn mandem
(mandem)
Ayé ò le, ọmọ Ọba kí ẹ
Ìwọ ló ní owó inú bank ẹ
Hold something
Osu lapa bi
O jí, ó bá eba, àti àmàlà Peckham
Everybody know it’s a vibe
Gbajúgbajà ìlú mo ká yìí
Ó ń gbé won lo free ride
Ó ń sunu this side
Bóbo kò ń pẹ̀dé ọmọ mi pro
Bobo alashashaka
Ẹ ma wo Ìjọ L’ẹsẹ́ negro
Mandem
Tó ń gbó vibe, kò ṣe ní jó
Haibo
Ti awon arab gan o se ko
Eni ni ìgbàgbó, pé ọjà ilé yàtọ̀
Ó kọ́ kan mí ní ìpàkò
What you saying, I’m going fam
Written by: Samuel Ashaye
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...