Lyrics

Seribumi Seribumi elédè kewu (Shocker lo ṣe beats) Iji ra Qdot lórúkọ tèmi Qdot lórúko mí oohh, eh-oh Àyé là bowó (ayé là bowó) Àyé là má fí silẹ lọ (silẹ lọ) Ayànmọ pẹlú kádàrá wọn yàtọ sírà wọn Òní k'ajá má gbé nílé, ó yàn kinihun sínú igbó T'óbá lówó ló d'àwo ilé àyé (yeah oh, e eh-eh) O lówó lọwọ, ó d'ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé?) Olówó l'ayé má fún láyè, torí olówó l'ayé fẹ rí Ẹlẹdàá mí o ṣemí lẹni àyé fẹ rí (Ẹlẹdà mí, oh-ohh) Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Ero mí tó ń jò, tó ń jo lórí omi Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ'run lóbá mí ṣe (yay) Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọ'run lóbá mí ṣe Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Ọrẹ, wo, owó lafi ń ṣe ilé àyé Ìwà ló má fi ń ṣe ọrùn (fi ń ṣe ọrun) Bóṣé lówó tó o, lomá gbádùn òyìnbó to Lomú Davido ọmọ Bàbá Olówó pariwo p'owó ní kókó Money good ohh, ohh Poverty no sweet oh, my brother T'óbá lówó lo d'àwo ilé àyé (ooh, ooh, yeah-yeah-yeah) Ó lówó lọwọ ó d'ẹrù àyé (ahn-ahn, kílódé o?) Olówó láyé má fún láyè, torí olówó láyé fẹ rí Ẹlẹdàá mí oh, ṣemí lẹni àyé fẹ rí Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi (ayy-ayy, oh) Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Ẹní lulu fún ń bẹ nísàlẹ̀ odò, ṣébí Ọlọrun lóbá mí ṣe (bá mí ṣe) Ero mí tó ń jò, tó ń jò lórí omi Àyé dùn (àyé dùn jẹ jù'yà lọ) Àyé yí dùn (àyé dùn jẹ jù'yà lọ) Orí ṣe mí l'olówó àyé (àyé dùn jẹ jù'yà lọ) Bí tí Wasiu Ayinde o (àyé dùn jẹ jù'yà lọ) Bí tí K1 De Ultimate (àyé dùn jẹ jù'yà lọ) Shout out to Mayegun gbogbo ilé Yorùbá Yeah, who's here?
Writer(s): Fakoya Oluwadamilare, Mudashiru Olajide Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out