Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
BhadBoi OML
BhadBoi OML
Vocals
Qdot
Qdot
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Kuham Oladimeji Akinyinka
Kuham Oladimeji Akinyinka
Songwriter
Qudus Fakoya Oluwadamilare
Qudus Fakoya Oluwadamilare
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Damilola "Dapper" Akinwunmi
Damilola "Dapper" Akinwunmi
Executive Producer
Dibs
Dibs
Producer

Lyrics

[Intro]
Alimanjiri oh oh
Alimanjiri
Aṣiri a bo oh oh
Alimanjiri oh oh
Alimanjiri
Ọmọọmọ Mọriamọ
[Verse 1]
Kagani wana ƙolo
Ɓarawo banza
O ya ka ma lọle o bouncer
O ṣaarọ Monday ọga Ade
Ma wi, ma wi, emi o lowo Lambo
Emi kọ mo n gbowo Oando
Aṣiri a bo
Igba ti mi o yawo LAPO
[Chorus]
Asalamalekun
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Asalamalekun
Alimanjiri a seli papa (Babi Allah)
[Verse 2]
Daddy, daddy, daddy
For our country, country
Wọn rojọ NEPA ni daada
A e roju ẹlẹha ni gbangba
Ma wi, ma wi
[Chorus]
Iṣẹ agbe la fi n ball
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Asalamalekun
Alimanjiri a seli papa (Babi Allah)
Fẹjọ lẹ do transfer
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Bani batasi nebo
Alimanjiri a seli papa
[Verse 3]
Ẹ ye ma ba mi sọ
Ẹ ye ma ba mi sọrọ were tẹ ẹ le b'ọlọpaa sọ
Nawonawo lemi jẹ n wabi gba
Ki n dele ọrẹ mi (Dele ọrẹ mi)
Jide ọrẹ mi (Jide ọrẹ mi)
Alagbe ọrẹ mi (Alagbe orе mi)
Poco ọrẹ mi (Poco ọrẹ mi)
Gbowogbowo ọrẹ mi (Gbowogbowo ọrẹ mi)
[Chorus]
Iṣẹ agbe la fi n ball
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Asalamalekun
Alimanjiri a seli papa (Babi Allah)
Fẹjọ lẹ do transfer
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Bani batasi nebo
Alimanjiri a seli papa (Ọmọọmọ Mọriamọ)
[Verse 4]
Alimanjiri, ọmọ buruku ta a gbọdọ ma ji ri
Ẹnu o ra Richard Millie
Owo lo ma ko lẹ ko ma gbagidi
Ma kọja boundary
Ki n ma ba lu ẹ bi ilu bandiri
In kina son kuɗi Allah bamu saʼa
Ya bamu kuɗi
Wait, ọmọ Ibo (Ibo)
Jẹ ka lala skibo (Skibo)
Fi si nwaju, fi si lẹyin lẹyin
To o ba ti fẹ joko leṣoo aṣiri a bo
Lọ gbowo lọwọ dildo (Babi Allah)
Mi o tẹwo (Babi Allah)
Allah bamu saʼa
Ẹ ye ma ba mi sọ
Ẹ ma ma ba mi sọ ọrọ were tẹ ẹle ba gomina sọ
Kọmọ pasitọ to jẹbọ
Iya to bimọ were ṣa lo ma tọ
Jẹ n gbọkada ki n dele ọrẹ mi (Dele ọrẹ mi)
Obelu ọrẹ mi
Dr Brown ọrẹ mi
Riliwanu Cooler ọrẹ mi
[Chorus]
Iṣẹ agbe la fi n ball
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Asalamalekun
Alimanjiri a seli papa (Babi Allah)
Fẹjọ lẹ do transfer
Alimanjiri a seli mama (Babi Allah)
Bani batasi nebo
Alimanjiri a seli papa (Babi Allah)
Written by: Kuham Oladimeji Akinyinka, Qudus Fakoya Oluwadamilare
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...