album cover
Ah!
81,539
World
Ah! was released on November 26, 2020 by YBBM as a part of the album Alagbe
album cover
AlbumAlagbe
Release DateNovember 26, 2020
LabelYBBM
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM125

Music Video

Music Video

Credits

Lyrics

[Intro]
Kuro n'bẹ yẹn na
2T on the Mix
[Verse 1]
Awilo ko wa lowo lọ o, pẹlu je m'appelle, comment tu t'appelles?
Qdot lorukọ mi
Ifa to fi talaka jọba
Ẹnu ifa gan-an ma gbẹ
Talaka onikaramọ
Ewo ni pe Benz n jepo
Tẹ ba lowo lọwọ mọ ẹ jẹ a mọ
N'gba tẹ n gbowo ẹ dawa mọ
Ma tẹle ẹnu
Scam l'ọba lọla
Baby I no cum
You, you no cum
How come belle come
Lekki o jina s'Ẹlẹkọ
Lalẹ Jimoh
T'ọmọ yin o ba sunle
O ti lọ ba wọn jojo 'of lay lay'
A mọ awọn to n lẹdi mọ
[Verse 2]
Okoko, dakun ma yinbọn
Yasin ko funny
Bawo l'ọn ṣe gbe Ramoni?
Iyẹn mo ṣe ja fun korope
T'owo ba pe, k'ori ma pe
Awọn kan l'ọn ṣe birisope
Ye ba wọn daṣa p'aye fẹlẹ
Aye gan-an o fẹlẹ n'Ibadan
[Verse 3]
O ya choko ri choko
Karimọ gbọkọgbọkọ
To ba ti fẹ bill mi
Lo ma ma lo pics mi
Baby o dẹ sub fun mi
O dẹ gba shop fun mi
Jọ ṣo pa'yan fun mi ni
[Verse 4]
I'm not your father
And you not my mother
Rọra mọti Apọngbọn
Ko ma pada laju s'Alagbọn
[Verse 5]
Ọmọ ọgbọn
Ko fẹ la Tirebo
O ti ri gọlugọ
O n ṣebi Abẹni Agbọn
O wa lọ n dun ṣio-ṣio
Mario, kilo, kilo
Mi o lo picker mọ
Small Dokita mi o gun speaker mọ
Ta lo n ba yin ja? D'ẹgbẹ Olubadan mi o wọ nicker mọ
[Verse 6]
Ẹ duro na o tun ti d'ogun
Omi kolo o tun ti gbe mu
Ori wa n sare j'ẹsẹ lọ
Aye dun jẹ ju iya lọ
Agbọn ta'yan ju ijalọ
[Verse 7]
Skelende to n fa shisha oh
Ọmọ Mushin to n na teacher oh
Ẹgba lo l'Onikolobo
Kini yẹn o jina si idodo
Ikorodu o jina si Igbogbo
Ikọtun wọnu Ejigbo
Ma lọ gbẹran iya mi l'Oshogbo
[Verse 8]
Ahn, Ibadan lo mọ
O mọ Laipo
Ijapa lo mọ
O mọ Yannibo
Maalu ja wọ'ja
Ẹni kọ'ja ma tuka
Japa bo ri jacketi pupa
[Verse 9]
Awilo ko wa lowo lọ
Pẹlu je m'appelle
Comment tu t’appelles?
Ani o ma jaa, ti n ba tu tabẹ
[Verse 10]
Dende n'Ilaro
MC Oluomo
Lanre Typical
Ooṣa ni Baddy Ooṣa
Iko Modina
Hot Water ni Mile 2
Alhaja Orimọlade
Eeyan Paso l'Omole
Billy Hustle ọmọ Salawe
Climax n ṣe visa
Tata Emeka
Azeezah Oshoala
Tori mo mọ Miss Bottles
Ikorodu laye wa oh
K Sir Sosse
Arowolo
Eyi to n ta mọto
Awọn t'emi l'America oh
Alaṣẹ Nikas Teni level
Abul Abel
Slay Papa
Jaye Success
Mo mọ Makinde
CEO, Naijaloaded
Ọmọba Kumasi
Ọrọpọ nilu Ghana
Mo mọ Owo Mabo
Femi Jaguar
Laborita
Mo mọ Sir Kuti
Ẹ ma jẹyẹn na
To ba bajẹ kẹ gbe lena
Kuro nibẹ yẹn na
Barrister o play nibẹ yẹn mọ
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...