Créditos
PERFORMING ARTISTS
Azeez Fashola
Vocals
Chisom Ezeh
Programming
COMPOSITION & LYRICS
Azeez Fashola
Lyrics
Chisom Ezeh
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Chisom Ezeh
Producer
Mark Dobson
Mastering Engineer
Letras
[Intro]
Ẹ gba mi, awọn ọmọ Naija fe f'idi pa mi (Wọn fe fi idi pa mi)
Control the crowd, control the crowd
Marlians comeforward, the rest fuck off, ṣo ye ẹ
Yo Rexxie pon this one
[Verse 1]
Eeee ẹ gba mi, awọn ọmọ Naija wọn fẹ fi idi pa mi (Wọn fe fi idi pa mi)
Nigbami ti'n ba ṣi Insta idi ma ni (Idi ma ni)
Idi Araba, Idi Oro, idi abajọ, Idi Arere, idi ganlebe, Idimu
Gbe'di jọ t'ani idi ofo (T'ani idi ofo)
Ah! ẹ ni sun
Ma lo tẹ idi gbabe nipple (Gbabe nipple)
Ye oh baby, masa gbori duro yọdi fun (Yọdi fun)
Wọn ti settle ẹ
Abu Abel ti settle e (Settle e)
Samuel Larry ti settle e (Settle e)
Baddosneh ti settle e (Settle e)
[Verse 2]
Inside life, ninu aye rayeraye (Aye raye)
Aye tun ya to s'aye
K'Olọhun ma je ka r'ija aye (Ka r'ija aye)
Ninu aye, aye tun jẹju aye
Ṣẹ ẹ r'oju aye, mo r'aye mo sa faye
[Chorus]
Tú eres una puta
Baby girl you are puta
Imagine lalẹ ana, Rexxie fi benzo gbe Ruka lo
Ṣo ti mu'gbo yo ni, oloṣo ṣe ma loyun fun mi – What can fa?
Ṣo ti mu cocaine abi'o ko ni catarrh
[Verse 3]
T'agbo yẹn ba dull, iwọ play Naira Marley o ma scatter ṣa
Awa no manners, zero belts, a thousand trousers
Ṣo mo MD iyẹn mean ko jo Marlian Dance
Ṣo ri NBG ma so tan, awa No Belt Gang
Kuron'bẹ, hello
[Bridge]
A mọra wa, a mọra wa
O fe ma magnet but a mọra wa
Ẹ ma lọ wa, ẹ ma lọ wa, ma lọ wa
O wanlẹ oh, ẹ ma lọ wa
[Chorus]
Tú eres una puta
Baby girl you are puta
Kalapoka, baby girl you are puta
Tú eres una puta, puta pu
Baby girl you are puta, puta
Kalapoka, poka, baby girl you are puta, puta
[Verse 4]
Tori pe ara ti kun, tori pe ara mi wa lọna
Just because you know that I want to ṣọwọ kan (Mo fe ṣe ọwọ kan)
You want me to spend the money, your daddy can't spend on you (Can't spend on you)
Don't call me to tell me rubbish wipe o ni fẹ mi (Pe o fẹran who?)
If you catch a thief in the act o ma ni oun o ni ṣe iru ẹ mọ (Ko ni ṣe iru ẹ mọ)
Ọmọ t'ọn sọfun ton warunki ita la ti kọgbọn (Kon ko lo gbọn)
If you don't know how the water get in the coconut (In the coconut)
Mo n kan sọfun wipe ko mọ b'omi ṣe n de inu agbọn
[Chorus]
Tú eres una puta
Baby girl you are puta
Kalapoka, baby girl you are puta
Tú eres una puta, puta pu
Baby girl you are puta, puta
Kalapoka, poka, baby girl you are puta, puta
[Bridge]
A mọra wa, a mọra wa (A mọra wa, a mọra wa)
O fẹ ma magnet but a mọra wa (A mọra wa)
Ẹ ma lọ wa, e ma lo wa (Ẹ ma lọ wa, ẹ ma lọ wa)
O wanlẹ oh, ẹ ma lọ wa
[Outro]
Yo Rexxie pon this one!
Yo Rexxie on this one!
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh