Vídeo musical
Créditos
PERFORMING ARTISTS
Atunbi
Performer
Oladunjoye Olabode
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oladunjoye Olabode
Songwriter
Letras
It's femsy the beat chef
(Wawawu wá wà wá, àwọn onísọkuso ó sọ bilẹjẹ, olúwa kò wá yọ)
Ẹníkà, ayé tó ńṣe gudu méje, ẹníkà
(Sàpátápàrá là síntọ́)
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà oh, ẹníkà
(Ẹnu mẹ'fà, méje-méje)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'áyé má mà mún mi
Torí kà, torí kà, torí kà
(K'áyé má ba mún wa)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
Eh, wọ́n níkà
Ayé tó ńṣe gudu méje, wọ́n níkà
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà eh, ẹníkà
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
Summer ni mo lọ
Mi ò ti ẹ̀ ró pé
Mo ma pẹ́ dé oh
Torí mi ò kí n pẹ́ dé
Ọrọ' ló ṣe bí ọrọ' (lo ṣe bí ọrọ' sẹ)
Èrò ni ò tètè parapọ'
Torí mi ò kí n pẹ́ dé
Ọkàn mi wá nílé ó (ó wà nílé)
Torí mi o kí n pẹ́ dé
Ṣa dédé mo gbọ́ 'ròyìn
Pé ó ti gbowó wá sálọ (ehn en)
Gbogbo ẹni t'ófẹ́ k'awálẹ́ o
Ẹ ò ní dúró sókè (Àṣẹ)
Torí
I'm a superstar, ẹ gbà bẹ̀
Ní summer mo lọ
Bí mo ṣé ma ń lọ (lọ)
On my way to Polokwane oh
Mo lọ Bushbuckridge
Mo sùn sí Hazyview
I saw that guy from Anambra
Eh, tree plantations everywhere
I love to see them always
Ẹníkà, ayé tó ń ṣe gudu méje, ẹníkà
(Sàpátápàrá là síntọ́)
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà oh, ẹníkà
(Ẹnu mẹ'fà, méje-méje)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'áyé má mà mún mi
Torí kà, torí kà, torí kà
(K'áyé má ba mún wa)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
Eh, wọ́n níkà
Ayé tó ńṣe gudu méje, wọ́n níkà
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà eh, wọn níkà
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
Kò wá s'ọ́nà t'ẹlè gbe gbà o
Mo ti de, mo ti de, mo ti de
Torí
I'm a superstar, ẹ gbà bẹ̀
Ẹya gba bẹ (ẹ yà gba bẹ ṣ'ẹgbọ)
Ìdá kan ò lè dámi dúró
Mo ti dé, mo ti dé, mo ti dé
Mo gbówó dé, mo gbọ́lá dé
Mo gbọ́là dé
Ẹ ò lè dámi dúró
Torí
I'm a superstar, ẹ lọ mọ bẹ
Ẹníkà, ayé tó ń ṣe gudu méje, ẹníkà
(Sàpátápàrá là síntọ́)
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà oh, ẹníkà
(Ẹnu mẹ'fà, méje-méje)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'áyé má mà mún mi
Torí kà, torí kà, torí kà
(K'áyé má ba mún wa)
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
Eh, wọ́n níkà
Ayé tó ńṣe gudu méje, wọ́n níkà
Pẹ̀lú yàyà mẹ'fà eh, wọn níkà
Ẹ̀bẹ̀ mo mà b'ayé o
K'aye má mà mún mi
It's femsy the beat chef
Writer(s): Oladunjoye Olabode
Lyrics powered by www.musixmatch.com