Letras

Eh eh eh, eh eh eh Ah ah ah, ah ah ah ah Oh oh oh, oh oh oh oh Mori iyanu, eh eh, iyanu Mori iyanu, eh eh, iyanu Eh eh eh, eh eh eh Ah ah ah, ah ah ah ah Oh oh oh, oh oh oh oh Mori iyanu, eh eh, iyanu Mori iyanu, eh eh, iyanu Bawon kan ba Kuse nigba kan laye won To ba d'olowo, wọn sọ wipe iyanu ni B'elo miran ba yàgan ri to ba wa d'olomo eh eh Wọn sope iyanu ni, lootọ ni, iyanu ni B'oko bá danu to run jege, teni kankan o f'arapa Eni orí re pe ni'le taropin t'ọlọrun wa gbégbá Tabi ẹni to gbojo iku to palemo ti o pada wa ku mọ Gbogbo rẹ loje iyanu, eh eh o, iyanu ni Eh eh eh, eh eh eh (gbogbo re lo je iyanu) Ah ah ah, ah ah ah ah (ninu Aye ta wa yi iyanu po repete) Oh oh oh, oh oh oh oh Mori iyanu, eh eh, iyanu (mori iyanu, emi ma ri yanu) Mori iyanu, ah ahh, iyanu Iyanu to se kenke, o ka mi laya titi Ilu kekere kan wa won o tọrọ jẹ bẹẹni wọn o la won sagbe Arabirin kan wa nibe ta jisẹ fún pe o ma bi iyanu Ẹda eniyan o le ro, pe iyanu le ti bẹ wa o Okuku sele bè abi iwọ naa, bi o ti le jo iyanu Sugbon bi ti ṣe jo iyanu to, ọba ilu kan wà kiri Obwa lati pa tori e o pa ọpọlọpọ ọmọ Egbo kini ijoloju ki lo fe fi ọmọ talakà se B'aye se ri niyẹn eni ma ga oju rẹ a ri to (Abi e o ri o) Eh eh eh, eh eh eh Ah ah ah, ah ah ah ah (ki lo lowo fe fi ọmọ talakà se o) Oh oh oh, oh oh oh oh (egbo na) Mori iyanu, eh eh, iyanu (emi ma ri yanu kan) Mori iyanu, ah ahh, iyanu Odagba (iyanu) Iṣẹ iyanu akọkọ (iyanu) Ni Canaan ti Galilee (iyanu) Ọrọ ninu tempili (iyanu) Oku ọmọ Jairu (iyanu) Bartelomew afọju nko (iyanu) Oda eti pada f'eleti (aikaka tan nise iyanu) Ìyanu tó ga to jo emi loju ju o Won da baraba sile awọn alaiṣẹ o ma ṣe o Ikan o ba kan ekunrere ata ti ọsẹ fi bójú Pari pari re lori igi agbelebu lo ba so p'otan A ba ori (iyanu) A ro ni lára lile (iyanu) Iya eyi gan gan (iyanu) Abeni l'owe ekun ti (iyanu) Iyanu wo lo to eyi ka bi eniyan tori ese araye Iyanu wo lo to yi o ki a so mo nu tori ẹlẹsẹ pataki M ba je awa lohun se ale se, eje a bi'ra wa Ka ma dénú ako iṣẹ o Oba wa ni iyanu Eh eh eh, eh eh eh (ọjọ mi loju ju) Ah ah ah, ah ah ah ah (mi o le sa kawe rara) Oh oh oh, oh oh oh oh Mori iyanu, eh eh, iyanu (ah iyanu to lami lenu sile) Mori iyanu, ah ahh, iyanu ni Ko sagbon ko se tutu to kọjá ẹni f'ẹmi rẹ le'lẹ Ko tún sí ìfẹ atata kan tó dàbí ìfẹ oluwa Abi eni wa saye lati wa kese ayé gbogbo lọ Ko tún sí iyanu miran mo, eyi ni yanu Oku asi sìn, ojijakadi ni saare O gba Kokoro lọwọ ikú, ọ gbe iku mi ni isegun Iku oro re da óò, isa oku isegun re da óò Ora ìyè aráyé ni Igbo ku, ojinde lojo keta (oluwa ji o) Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni tó fẹ iye ko ka lo Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo Itan iyanu t'ife nla le yi o Lato do asèdá, eledua baba wa Eni to fi ọmọ rẹ ra arayé pada Agba iyanu tobi iyanu teni yan ri Iyan iyanu t'ife nla leyi o Latodo asèdá eledua baba wa Eni fi ìfẹ hàn wá ti o fẹ ká parun Agba iyanu to bi iyanu teni yan ri Itan iyanu t'ife nla leyi La tọwọ ife eledua baba Eni gbawa sile to f'ọmọ kan soso sa awotan ẹsẹ wa Agba iyanu to ni iyanu teni Yan n ri
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out