Créditos
ARTISTAS INTÉRPRETES
D'banj
Intérprete
COMPOSICIÓN Y LETRA
Daniel Oyebanjo
Autoría
Oluwafemi Oladapo
Autoría
Victor Okafor
Autoría
Letra
[Intro]
Saint Sami Ganjah, Saint Sami Ganjah
O ya slow down on a codeine diet
Ọtunba Lamba lo n sọrọ
Champagne melo? XO melo? Ọlọrun
Ọja ma jẹ mi now, ọmọ ase to wa lẹgbẹ mi ni o jẹ
Baba ẹ motherfucker, ooooohhhhhh
Kachi kachi kachi kachi kachi kachi kachi kachi kachi
[Verse 1]
Tawọn boys ba tẹwọ gbọpẹ kilo ku?
Ka ṣana wọle
Wo ina Ọlọrun lori casket bi pọdun ti de
[PreChorus]
Ebelesun eeyan Charles Okocha
Mo ti manya wu, mo ti mezenbu mo ti kpef gan-an, okay
So therefore issa banger
Banga Lee issa banger
Mr Real lẹgbẹgbẹ issa banger
Slimcase oshozondi issa banger
[Chorus]
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
[Verse 2]
Banga Lee in a Porsche
Oh baby ma lọ rush
Mo ṣe ti Mainland, mo ṣe ti Island, mo tun cover awọn street
Mo wọle pẹlu Gucci pẹlu fila to fana kọja
Emi naa kọ, Ọlọrun lo ko ijọba yii fun mi, filẹ
O ṣa prapra, o ṣa propro
O ni wọnu Benz ko tun d'akoto
Ṣo le gbe iya yẹn, ṣẹnu ẹ bo?
Oshozondi baba in the game ẹja nla
[PreChorus]
Ebelesun eeyan Charles Okocha
Mo ti manya wu, mo ti mezenbu mo ti kpef gan-an, okay
So therefore issa banger
Banga Lee issa banger
Mr Real lẹgbẹgbẹ issa banger
Slimcase oshozondi issa banger
[Chorus]
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
[Verse 3]
Banga Lee welcome to Mainland
Ṣakuṣaku on the Island
Okoro you don pop Rozay?
You no get money, go sell your papa land
Awọn aboki wọn ti ẹ ja
Wọn ti gbo story ni, wọn ki i wo tele' ni?
Ẹ ki i ka paper ni?
Ask about me Koko Master
They go tell you how I dey runtown
Log in Instagram na the banger dey for town
[Verse 4]
Tawọn boys ba tẹwọ gbọpẹ kilo ku?
Ka ṣana wọle
Wo ina Ọlọrun lori casket bi pọdun ti de
[PreChorus]
Ebelesun eeyan Charles Okocha
Mo ti manya wu, mo ti mezenbu mo ti kpef gan-an, okay
So therefore issa banger
Banga Lee issa banger
Mr Real lẹgbẹgbẹ issa banger
Slimcase oshozondi issa banger
[Chorus]
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
Issa banger
Issa banger
Issa banger
So therefore sure banger
Written by: Daniel Oyebanjo, Oladapo Oluwafemi Oko-eko, Oluwafemi Oladapo, Victor Okafor