Créditos
ARTISTAS INTÉRPRETES
Dj Tainny
Intérprete
COMPOSICIÓN Y LETRA
Min.Oluwaferanmi
Composición
Letra
[Verse 1]
Baba ẹ bẹrẹ latori mi
Iṣẹ iyanu ti o ṣẹlẹ ri lẹbi mi
Baba ẹ bẹrẹ latori mi
Iṣẹ iyanu ti o ṣẹlẹ ri lẹbi mi
Ehn, Baba ẹ bẹrẹ latori mi
Iṣẹ iyanu ti o ṣẹlẹ ri lẹbi mi
Baba ẹ bẹrẹ latori mi
Iṣẹ iyanu ti o ṣẹlẹ ri
Ehn ehn ehn
Baba ẹ bẹrẹ latori mi
Iṣẹ iyanu ti o ṣẹlẹ ri
[Verse 2]
Ọba ti o pe meji
Ọba ti o lorogun
Ọba ti o lafijọ o
Iba rẹ o Baba
Ọba ti o pe meji
Ọba ti o lorogun
Ọba ti o lafijọ o
Iba rẹ o Baba
Baba ti o pe meji
Ọba ti o lorogun
Ọba ti o lafijọ o
Iba rẹ o Baba
Ọba ti o pe meji
Ọba ti o lorogun
Ọba ti o lafijọ sẹ o
Iba rẹ o Baba
Written by: Min.Oluwaferanmi